RESTITUTION

THE SEED
“For they have sown the wind and they shall reap the whirlwind: it hath no stalk, the bud shall yield no meal, if so be it yield, the strangers shall swallow it up.” Hosea 8:7

It’s the right thing to do as Christians, to give back to the owner whatever we have taken away from them, because the word of God cannot be broken (Galatians 6:7) whatsoever you sow, you shall reap. Restitution is the act of making right the wrong done against someone or an institution. The two basics of restitution are material and personal loss. In any form it may be, we must be ready to make it right, back to the owner. this is the standard of God. There are two ways about it, understand your degree of offense and make efforts to compensate satisfactorily.

BIBLE READING: 2 Samuel 12 : 1 – 7

PRAYER: Father give me the strength and ability to be able to rectitude my wrong.

                                                         ÀTÚNṢE

IRUGBIN NAA

Nitori wọn ti gbìn ẹ̀fuufu, wọn o sí ká āja: ko ní ìgi ọ̀ka: irisi kí yíó sí mú oúnjẹ wá: bí o bá ṣe pé o mu wa, alejò yíó gbé é mí.” Hosea 8:7

 

Ohun tó tọ́ gẹ́gẹ́ bí Kristẹni ní, láti fi ohunkóhun tí a bá gbà lọ́wọ́ ẹni tí o ni nkan rẹ padà fún un, nítorí pé a kò le ba ọ̀rọ̀ Ọlọ́run jẹ́. Galatia 6:7 Ohunkohun tí a bá gbìn, ni a o ka. Atunṣe jẹ ṣiṣe ẹtọ fún aṣiṣe ti a ṣe si ẹnikan tabi ile-lṣẹ kan. Awọn oriṣi atunṣe meji ti o wà jẹ ohun elo ati ti ara ni tí ohun tí o sọnù. Ninu eyikeyi ti o le jẹ, a gbọdọ ṣetan lati ṣe awọn atunṣe tí o tọ pada si awọn ẹni tí o yẹ láti ṣe fún; eyi ni awọn ètò ti Ọlọrun. Awọn ọna meji lo wa nipa rẹ, rí wipe o ni oye iwọn ẹṣẹ rẹ, ki o sa  awọn ipa rẹ lati ṣe àtúnṣe ní ọnà tí o tọ àti bó ti yẹ.

BIBELI KIKA: 2 Samuẹli 12:1-7

ADURA: Baba fun mi ni agbara ati ipá lati le ṣe àtúnṣe lórí aṣiṣe mi, ni orúkọ Jesu amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *