GOD KEEP PROMISES

THE SEED
“And Abraham came near and said, “Would you also destroy the righteous with the wicked?” (Genesis 18 : 23)

 

Abraham had an awesome relationship with God, inspite of the fact that he goes childless. He knew God and God madehim a friend and promised to make him Father of Nations.

Just before the judgment of God came upon the cities of Sodom and Gomorrah, God made sure that Abraham, His friend, knew about it. In fact, Abraham boldly pleaded with God to reverse this judgment. This was indeed a demonstration of a great level of intimacy. It takes this kind of relationship to walk in abundance. God needs someone that can commune with Him on an intimate level to pick up the signals of His direction. The secrets of greatness in life comes naturally through divine relationship. When you know Him, He will reveal his secret and plan for you, even before carrying them out to the general public and you can even make a plea of Him and God will keep His promise.

BIBLE READING: Genesis 21 : 1 – 3

PRAYER: Father let me find favour in your sight and make me your friend.

 ỌLỌRUN MÁÀ NPA ÌLÉRÍ MỌ

IRUGBIN NAA

“Abrahamu sí sunmọ ọdọ rẹ̀, I sí wipe, iwọ o ha run olódodo pẹlu eniyan búburú?.” Genesisi 18:23

Abrahamu ni ibasepọ agbayanu pẹlú Ọlọrun bi o tilẹ jẹ pé kò ní ọmọ. Ò mọ Ọlọ́run, Ọlọ́run sì sọ ọ́ di ọ̀rẹ́, ó sì ṣèlérí láti sọ ọ́ di baba àwọn orílẹ̀-èdè.  Kí ìdájọ́ Ọlọ́run tó dé sórí àwọn ìlú Sódómù àti Gòmórà, Ọlọ́run rí i dájú pé Ábúráhámù ọ̀rẹ́ Rẹ̀ mọ̀ nípa rẹ̀. Ni òtítọ, Abraham fi ìgboyà bẹbẹ lọdọ Ọlọrun, lati yi idajọ yii pada. Eyi jẹ ifihan tootọ ti ipele irẹpọ nla laarin Ọlọrun àti Abrahamu.   Irú irẹpọ yi gbani láàyè lati rìn ninu ọpọ yanturu ohun ini. Ọlọrun nilo ẹnikan ti o le ba a sọrọ ni ìpele timọtimọ lati le gba awọn ifihan agbara ti itọsọna Rẹ. Àwọn àṣírí láti di nlá nínú ayé, wá  nipasẹ ibaṣepọ àtoke wa.  Nígbàtí o ba mọ ọ. Oun yíò tu asiri ati èrò ti O ni lọkàn fun ọ ṣáájú ki o to gbé wọn jáde sí gbogbo ènìyàn; ati pé o le bẹbẹ lọwọ Rẹ, Ọlọrun yíó sí mu ileri rẹ ṣẹ.

BIBELI KIKA: Jẹ́nẹ́sísì 21:1-3

ADURA: Baba jẹ ki n ri oju rere lọdọ rẹ ki o si sọ mi di ọrẹ Rẹ

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *