THE SEED
“LORD, do not rebuke me in your anger or discipline me in your wrath.” Psalms 6:1 NIV
When we find ourselves in wrongdoings as Christians, the wisest thing to do is to ask for mercy, it’s not a time to rationalise or justify our mistakes before God. This will only give the devil a foothold to keep us from receiving the mercy of God. It is the mercy of God through Jesus Christ that can save us from being judged mercilessly. The opening verse of Psalm 6 echoes a heartfelt plea for God’s mercy and understanding. It’s a reminder that in times of struggle and sin, we can turn to the Lord with a humble heart. In our lives, we may sometimes feel the weight of our wrongdoings. We might fear divine discipline, but let us remember that our God is a loving Father. He disciplines us not out of anger but out of love.
So, when we pray Psalm 6:1, we seek God’s mercy, understanding that His discipline aims to correct us and bring us back into His loving embrace. Let us approach God with open hearts, acknowledging our imperfections and trusting in His boundless love and grace. He is a God of forgiveness and restoration. In our humility and repentance, we find the assurance that His discipline leads us to a closer and more intimate walk with Him.
BIBLE READINGS: Psalms 6:1-4
PRAYER: Heavenly Father, help me to be true to myself in my wrongdoing to humbly seek your mercy in Jesus’ name. Amen
NÍGBÀTÍ A BA DA ÈṢÈ
IRUGBIN NAA
“Olùwà ma ṣe ba mi wí ninu ìbínú Rẹ̀ tàbi nínú gbígbóná ibanujè rẹ”. Psalm 6:1
Ti a ba rí ará wa ninu àṣìṣe gẹ́gẹ́ bí Kristẹni, ohùn ti o jẹ ọgbọ́n julọ lati se ni pé lati béèrè fún àánú, Ki ìṣe àsìkò láti ṣe awawi tàbi ṣe ododo ará ẹni lori àṣìṣe niwaju Ọlọ́run. Èyí yio fún èṣù laaye lati dẹ́kun wa ni gbígbà àánú lọdọ Ọlọrun. Oore ọ̀fẹ́ Ọlọrun nípasẹ̀ Kristi nikan ní o le gbà wá kúrò nínú ìdájọ́ alailaanu . Ìbẹ̀rẹ̀ psalmu ori kẹfà (6) kéde ẹ̀bẹ̀ ti o mi ni lọ́kàn si Ọlọhun fún àánú àti òye. Èyí nranwa leti pé ni akoko ìlà kàkà ati ẹṣẹ ki a bá lè wa síwájú Oluwa pẹ̀lú irele ọkàn. Nígbà miran nínu ayé wa, a lé ni ìmọ̀lára ẹrú aisedeede wa. A lé ni ìbẹrù atoke wá, ṣùgbọ́n ki a mọ̀ pé Ọlọrun wa bàbà onife ni. Kii nba wa wí nínu ìbínú ṣùgbọ́n nínu ìfẹ́. Nigbati a ba gbàdúrà psalm 6:1, a nwa àánú Ọlọ́run, oye wípé ìbáwí Rẹ̀ tọ́ka sí titọ wa sọ́nà ati lati mu wa padà sínú ìyọ́nú sì Rẹ̀ ti o ni ìfẹ́. Ẹ jẹ́kí a sun mọ Ọlọ́run pẹ̀lú ọkàn ti o ṣí silẹ, mí mọ rírí àìpé wa ati nini ìgbẹ́kẹ̀lé ninu ifẹ ati oore-ofe Rẹ̀ ti ko ni òṣùwọ̀n. Ọlọ́run ti O ndariji ti o si nmu ni pada si po. Ninu ipò ìrẹ̀lẹ̀ wa ati ìrònúpìwàdà, a ri ìdánilójú pé ìbáwí mú wa sunmọ ati rin ni tímọ́tìmọ́ pẹ̀lú Rẹ̀.
BIBELI KIKA: Psalm 6:1-4
ADURA: Baba wa ti nbẹ ni ọrùn, ran mi lọ́wọ́ láti jẹ olotitọ́ si ará mi ninu aisedeede mi lati fi ìrẹ̀lẹ̀ wa àánú Rẹ̀ ni orúkọ Jésù Amin.