THE SEED
“I will give thanks to you, LORD, with all my heart; I will tell of all your wonderful deeds. I will be glad and rejoice in you; I will sing the praises of your name, O Most High.” Psalms 9:1-2 NIV
The above scripture is the words of King David when he lost a son. This establishes the fact that giving thanks to God is not conditional but an act to be performed at all times even when things and situations with us are not going on as expected. In expectations and when passing through the fire and rivers of life, in great challenges of sickness, losses of loved ones and jobs. The name of God must be praised by His Children, knowing with an understanding that God knows and has reasons for allowing such in our lives. Giving thanks to God always is a habit that should be cultivated and practised by all Christians. The Psalmist gave thanks to God further in verses 3-6 on past victories. Appreciating God for past victories and breakthroughs is an assured key to opening the door to victory in our present or future challenges.
BIBLE READINGS: Psalms 9:3-6
PRAYER: Lord, please keep me in the attitude of praise to you without any bounds. Amen
SÍBẸ̀, EMI O DÚPẸ́ FÚN UN.
IRUGBIN NAA
Emi o fi ọpẹ fún Ọ OLÚWA, pẹ̀lú gbogbo ọkàn mi, ngo ròyìn gbogbo ìṣe iyanu Rẹ̀. Emi o yọ èmi o si ṣe àjọyo ninu Rẹ̀; emi o kọrin ìyìn si orúkọ Rẹ̀ ìwọ ọga ògo julọ. Psalmu 9:1-2.
Ẹsẹ BIBELI tí òkè yí ni àwọn ọ̀rọ̀ Dáfídì ọba nigbati o pàdánù ọmọkùnrin rẹ. Eyi fi ìdí rẹ múlẹ̀ pe fifi ọpẹ fún Ọlọ́run kìí ṣe ohùn ti a le maa ṣe nígbàtí o ba wun wá, ṣùgbọ́n ìṣe ti a gbọdọ máà ṣe nígbàtí àwọn ohùn ti a nla kọjá ko rí bí a ti nfẹ. Nínú ìrètí ati nigbati a ńlá ina ati omi ayé kọjá, ninu ìdààmú ńlá ti àìsàn, pípadànu àwọn ẹni ti a fẹ́ràn àti àwọn iṣẹ́ òójọ́ wa. Orúkọ Ọlọ́run ní ki a yìn lati ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ Rẹ̀, ní ìmọ̀ àti òye pé Ọlọ́run mọ̀ ati pé O ni eredi ti o fi gba irú ìṣẹ̀lẹ̀ bẹ́ẹ̀ láàyè ninu ayé wa. Fífi ọpẹ fún Ọlọ́run jẹ́ àṣà tí a níláti fi si ojúṣe ti gbogbo Kristẹni sì gbọ́dọ̀ máà ṣé e. Oni psalmu fi ọpẹ fún Ọlọ́run síwájú sì i nínú ẹsẹ ìkẹta si ìkẹfa (v3-6) lórí àwọn ìṣẹ́gun tí ó ni sẹhin. Nípa mí mọ riri Ọlọ́run lori ìṣẹ́gun àti àwọn alaja ti o ni, eyi jẹ kọ́kọ́rọ́ ìdánilójú ti o ṣí ilẹ̀kùn fun iṣẹ́gun lori ipenija ìsinsìnyí àti tí ọjọ́ iwájú.
BIBELI KIKA: Psalmu 9:3-6
ADURA: Olúwa, jọ̀wọ́ fi mi sí ipa ọpẹ sí O èyí ti kó ní òpin. Àmín.