DO YOU FEEL FORSAKEN BY GOD?

THE SEED

“Those who know your name trust in you, for you, LORD, have never forsaken those who seek you.” Psalms 9:10 NIV

Unpalatable situations may put this thought in your mind, it might be because of long-standing challenges or God’s promises that are yet to be fulfilled in your life. Whatever your situation, be assured that God doesn’t forsake His people. If you are sure in your mind that you belong to Christ then take consolation in the Scripture above. All you need to do is to trust God that He will sort you out, answer your prayers, fulfil His promises and make things go well for you in due season, at God’s appointed time and not at your expected time. Don’t disconnect yourself from God to seek other solution because there’s no other genuine alternative to God. All other alternatives may seem genuine at first but if you look closely you will discover that they are laid traps of the enemy to pull you out of your trust in the Lord. Prophet Isaiah reminds us in the

BIBLE READINGS:  Isaiah 49:13-16

PRAYER: Lord Jesus, help me to not entertain an evil thought in my mind, let me keep trusting and believing in you that you can never forget me. Amen

 

ǸJẸ́ O NI IMỌ LÁRA PE ỌLỌ́RUN KỌ̀ Ọ SILẸ?

IRUGBIN NAA

“Gbogbo àwọn tí ó mọ orúkọ Rẹ̀ gbẹkẹle Ọ. Oluwa, ko tii kọ àwọn ti wọn  nwa Ọ silẹ” Psalmu 9:10.

Awọn ìrírí ti kó dùn mọ́ ni yí le fí ero yí si ọkàn rẹ, o lé jẹ́ àwọn ipenija ọlọjọ pípẹ tàbí ìlérí Ọlọ́run ti o n duro fún ìmúẹ. Ohunkohun tó wun kí ó lé máà la kọjá, ni ìdánilójú pé Ọlọrun ko kọ àwọn èniyàn rẹ̀ silẹ. Ti o bá ní ìdánilójú ninu ọkàn rẹ pé o jẹ́ ti Kristi, ni ìtùnú nínú ẹkọ kíkà ti a kà ni Ìbẹ̀rẹ̀. Ohun tí ó ni lo ni pe ki o gbẹkẹle Ọlọ́run ti yio  tun ohùn gbogbo e  fún   ọ, yíò mu gbogbo ìlérí ẹ ti yíò mú ohùngbogbo lọ déédéé ni àsìkò, ni àkókò Ọlọ́run ti  kìí e àkókò tí rẹ.

Mae yọ ara rẹ kúrò lọdọ Ọlọrun láti wa ọ̀nà àbáyọ miran nitoripe kó si ojúlówó ohun ti o dabi Ọlọ́run. Gbogbo okùn ọ̀tá làti já ọ  kúrò nínú ìgbẹ́kẹ̀lé rẹ nínú Olúwa. Wòlíì Isaiah rán wá  leti nínú iwe Is. 49:13-16 bi o tí òro fún Ọlọ́run lati  kọ wa silẹ gẹgẹ bi ọmọ Rẹ̀, nítorí O tí kọ wá si ori àtẹ́lẹwọ́ Rẹ. Olúwa ko jẹ gbagbe tàbí kọ wa silẹ. Ti o ko ba tii gbá ìdáhùn sí ẹ̀bẹ̀ àdúrà rẹ láti ọdọ Rẹ̀,  ni ìdánilójú pé O ńe iẹ́ lé e lori ní àsìkò tìrẹ yíò eé o o si ni ìẹ́gun àti alaja.

BIBELI KIKA: Isaiah 49:13-16

ADURA: Oluwa, ran mi lowo gba ero buburu laaye, je kin gbekele yin, kin si gbagbo pe iwo ki yio gbagbe mi. Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *