GOD IS FAITHFUL IN ALL

THE SEED

“We are afflicted in every way, but not crushed; perplexed, but not driven to despair; ” 2 Corinthians 4:8-9 ESV

Apostle Paul shared his experience and that of other believers around him with the Church in Corinth. He spoke of the faithfulness of God in all the negative experiences they had. He mentioned being afflicted in every way, yet they remained unbroken in their spirit to keep hope in Christ and in their determination to serve God till the end. Are you facing any affliction at the moment? They were perplexed, meaning that they had situations when they didn’t know what to do, just like you might have experienced or you are experiencing but they were not driven to discouragement because of God’s faithfulness. They also experienced persecution for spreading the gospel of Christ, they were beaten up, thrown to prison, humiliated and neglected by families and friends, but they were not neglected by God, they enjoyed fellowship with the Son and the direction of the Holy Spirit. lastly, Apostle Paul mentioned the highest price of being struck down but the faithfulness of God did not leave them to destruction. Beloved of Christ, whatever you are going through at the moment, if you truly carry the mark of Christ upon your life and you are obedient under Christ’s will you shall be like Mount Zion that can not be removed. Stand in God and you will experience the faithfulness of God.

BIBLE READINGS:  Psalm 125:1-4

PRAYER: Lord Jesus help me to hold on to you in all and enjoy your unfailing faithfulness all the days of my life. Amen

             NÍNÚ OHÙNGBOGBO

IRUGBIN NAA

A ń pọ́n wa lójú níhà gbogbo, ùgbọ́n ara kò ni wá: a ń dààmú wa, ùgbọ́n a kò sọ ìrètí nù. 9 A ń e inúnibíni sí wa, ùgbọ́n a kò kọ̀ wá sílẹ̀; a ń rẹ̀ wá sílẹ̀ ùgbọ́n a kò pa wá run. 2 Kọrinti 4:8-9

Nínu ẹ̀kọ́ kíkà ti o bẹ̀rẹ̀,  Paulu Àpọ́sítélì é àlàyé iriri rẹ àti tí àwọn onigbagbọ rẹ pẹ̀lú àwọn ìjọ tó wa ni Kọ́ríńtì. O sọ nípa ijolotitọ Ọlọ́run ninu gbogbo ìrírí wọn tí kò ba wọn lára mu ti wọn lakọjá. O sọ idaniloro ní gbogbo ọ̀nà, èyí nì pe  wọn ni ìjìyà tí ó lé ati ìrora làti ọwọ àwọn èniyàn, ojú ọjọ́ ti kó dára pẹ̀lú ai ni ìlera tó  pe ye ati bẹẹ bẹẹ lọ. Sibẹsibẹ ọkan wọ́n kó mí wọ́n ni ìrètí nínú KRISTI àti ìpinnu làti sin Ọlọ́run títí de òpin. Njẹ ó nnì ìdojúkọ lọ́wọ́ lọ́wọ́? Nwọn ni iporuru ọkàn,  èyí túmọ̀ sí pé wọ́n ní ìdojúkọ tí  wọ́n kó mọ ohùn ti wọn yíò e,  gẹgẹ bi irú ìlàkọjá tí o ti là kọjá tabi iru èyí tí ó ńlá kọjá lọwọ, wọ́n ko ni idaru ọkàn nitoripe Ọlọ́run jẹ olotitọ́. Wọn ni idaloro nítorí ìtàn kalẹ ìhín réré, a lú wọ́n, a sọ wọ́n sínú túbú, a dójú tí wọ́n, ẹbí àti ọ̀rẹ́ kọ wọ́n silẹ, ùgbọ́n Ọlọ́run kó kọ won silẹ: wọ́n é inú dídún ninú ìdápọ pẹ̀lú Ọlọ́run, wọ́n ni inú dídún si ìdápọ pẹ̀lú ọmọ Ọlọ́run ati ìdarí tí ẹmi mímọ. Lákótán Àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù dárúkọ èrè gíga ìwo lulẹ ùgbọ́n jíjẹ olotítọ Ọlọ́run sí wọ́n kó fí wọ́n silẹ fun ìparun. Ayanfẹ Kristi,  ohunkohun tí  o wù kí ó máa la kọjá lásìkò yí,  ti àmì Kristi bá nbẹ ni ara rẹ ti o si gbọ́ràn ni abẹ ìfẹ́ Kristi ìwọ yio dàbí oke Síónì ti a ko le i ni ìdí. Dúró nínú Olúwa ìwọ yíò sí ní ìrírí ijolotitọ Ọlọ́run ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́.

BIBELI KIKA: Psalmu 125:1-4

ADURA: Jésú Olùwà rannilọwọ làti di ọ mú àtadi gbádùn ijolotitọ tí kìí kùnà ni gbogbo ọjọ́ ayé mi. Àmín.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *