THERE’S NO OTHER MOUNTAIN OF REFUGE

THE SEED
“In the Lord I take refuge. How then can you say to me: “Flee like a bird to your mountain.” Psalms 11:1 NIV

The opening verse declares unwavering trust and faith in God. “In the Lord I take refuge.” Yet, the second part of the verse poses a question: “How then can you say to me: ‘Flee like a bird to your mountain’?” This question challenges us to consider where we turn in times of trouble. Do we flee to worldly solutions or find our refuge in God? Psalm 121:1-2 reaffirms this: “I lift my eyes to the mountains—where does my help come from? My help comes from the Lord, the Maker of heaven and earth.” This question could also come from the enemy if we do not know who we are in the Lord so that we can leave our legitimate place of refuge. We often encounter situations that urge us to run for safety, to escape like a bird to the mountains. But as believers, our ultimate safety is in the Lord. When we trust in Him, we will stand firm, knowing that God is our fortress, our refuge, and our strength. He provides strength when we are weak, protection when we are vulnerable and hope when we are in despair. We are called to stand strong in faith, for our God is greater than any challenge we might face. So, let this verse be a reminder to place our trust in the Lord. When fear or doubt tempts us to flee, let us remember that our true refuge is in God. He is our mountain, our unshakable fortress, and our constant source of hope and security.

BIBLE READINGS:  Psalm 121:1-4

PRAYER: Lord, Amid life’s storms and trials, help me to remain steadfast, for you are my refuge and mountain. Amen

KÒ SÌ OKE ÌSÁDI MÍRÀN

IRUGBIN NAA

Olúwa ni mo gbẹkẹ mi le: ẹ  ha ti ṣe wi fun  ọkàn mi pé, sá bí ẹyẹ lọ sí òkè yin? Orin Dafidi 11:1

Ẹsẹ tí ó bẹ̀rẹ̀ polongo ìgbẹ́kẹ̀lé àti ìgbàgbọ́ tí kì í yẹ̀ nínú Ọlọ́run.  “Ninu Oluwa ni ibi aabo. Sibẹ apa keji ti ẹsẹ Bibeli nà fi ibeere kan ranṣẹ: “Bawo ni o ṣe sọ fun mi pe: Sá bí ẹyẹ kan si òke rẹ?  Ìbéèrè yi fún  wa ni ipenija lati kiyesara fun ibí tí  a o gbé sá sí  ni ìgbà ìṣòro. Njẹ a máa ń sá fún ọ̀nà àbáyọ inu ayé tàbí à ńwá ààbò lọdọ Ọlọrun?  Sáàmù 121:1-2 fìdí èyí múlẹ̀ pé: “Emi o gbé ojú mi si ókè wọnnì, ibo ni ìrànlọ́wọ́ mi o ha ti wá?  Ìrànlọ́wọ́ mi ti ọ̀dọ̀ Olúwa wá, Ẹlẹ́dàá Ọ̀run àti Ayé.” Ìbéèrè yìí tún lè wá láti ọ̀dọ̀ ọ̀tá tí a kò bá mọ ẹni tí a jẹ́ nínú Olúwa kí a bá lè kúrò ní ibi ìsádi tí ó tọ.  Ni ọpọ ìgbà ni a máa ni ìdojúkọ ti yio mu wa sa lọ si ibi ààbò wa, sí sa asala bi ẹyẹ lọ sí ori oke. Ṣùgbọ́n gẹ́gẹ́ bi onígbàgbó, Oluwa ni aabo wa, Nigba ti a ba gbẹ́kẹ̀lé e, a o duro ṣinṣin, ki a mo pe Ọlọ́run ni odi wa, abo wa,  agbara wa. O n pese agbara nigba ti a ko lagbara, aabo nigba ti a ba wa ni ireti ati ireti nigbati a ba wa ni ai ni ireti. A pe wa lati duro pelu agbara ninu igbagbọ, nitori Ọlọrun wa tobi ju ipenija eyikeyi ti a le koju lọ. Nítorí èyí ẹ jẹ́ kí ẹsẹ Bíbélì yi jẹ́ ìránnilétí láti gbẹ́kẹ̀lé Olúwa nígbà tí ìbẹ̀rù tàbí iyèméjì bá dán wa wò láti sá, ẹ jẹ́ kí a rántí pé ààbò wa ń bẹ lọ́dọ̀ Ọlọ́run, òun ni òkè wa, odi agbára wa tí kò lè mì, àti orísun ìrètí àti ààbò wa nígbà gbogbo.

 

BIBELI KIKA: Psalmu 121 : 1-4

ADURA: Oluwa larin iji aye ati idanwo, ran mi lọ́wọ́ lati duro ṣinṣin, nitori ìwọ ni aabo ati oke mi.  Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *