THE SEED
“In My Father’s house are many mansions; if it were not so, I would have told you.”John 14: 2b NKJV
Jesus comforted His disciples with the promise of the future, he was going away to prepare a place for them in his Father’s mansion. The Paradise plan is for us to occupy the place He had gone to prepare, to receive us and for us to live there permanently. Ultimately, His joy will be to see us there. In V6, He told us that He is the way, the truth and life; but if we miss the way we won’t be occupying any room. Also, if we don’t abide in the truth and allow Him to live through us, we won’t get there and if we don’t we make him happy and His death is of no effect, wasted on us. No one knows how to tell us how to get to heaven like the one who lives there -V6. So, we must be eager to follow him to get there. Although we are not worthy, we are saved by grace, Eph 2:8 not by our works, God doesn’t want His mansion to be empty, so, He draws us by Himself through Jesus Christ. Let us strive towards righteousness, do away with deceits and in like manner we shall be in the mansion and enjoy the treasures we have laid and stored there.
BIBLE READINGS: John 14: 1-6
PRAYER: Heavenly Father, help me to walk in the way of truth and be guided into the beautiful mansion.
ILE TI O RẸWÀ
IRUGBIN NAA
Nítorí ni ilé bàbà mí ọpọlọpọ ibùgbé ni ó wà níbẹ̀: iba maṣe bẹ́ẹ̀, èmi ìbá tí sọ fún yín. Jòhánù 14:2b.
Jésù tu àwọn ọmọ ẹ̀yìn nínú pẹ̀lú ìlérí ọjọ́ iwájú tí òun yió lọ láti pèsè àyè sílẹ̀ fún wọn nínú ilé baba rẹ̀. Ètò Párádísè ni a pése fun wa láti gbe, ibi tí Ó ti lọ láti múra sílẹ̀, láti gbà wá, àti fún wa láti máa gbé níbẹ̀ títí láé. Ayọ RẸ ni lati ri wa nibẹ. Ni ẹsẹ kẹfa o sọ fun wa pe oun ni ọna, otitọ ati iye; ṣugbọn ti a ba padanu ọna náà, a ko ni le wa nínú ìkankan nínú àwọn yara wọnyi. Tí a ko ba duro ninu otitọ ati lati gbá a láàyè láti gbe inú wa, a ko ni le de ibẹ, ati pe, ti a ko ba mú inu Rẹ̀ dun, iku Rẹ̀ ki yio ní ipa lori wa, o já sí asán. Ko si ẹnikan ti o le sọ fun wa bi a ṣe le lọ si ọrun. gẹgẹbi ẹni ti o ti ń gbé ni ibẹ lati de ibẹ. A gbọdọ ni itara lati tẹle e lati de ibẹ; Bi otilẹjẹpe a ko yẹ, a gba wa la nipasẹ ore-ọfẹ, Efesu ori 2: 8 kii ṣe nipa awọn iṣẹ wa. Ọlọrun ko fẹ ki Ibugbe rẹ ṣòfò, nitori naa o fa wa funrararẹ nipasẹ Jesu Kristi. Ẹ jẹ ki a gbiyanju sipa ọna òdodo, láti mú ẹ̀tàn kúrò, bẹ́ẹ̀ náà ni a ó sì wà nínú ilé ńlá, a ó sì gbádùn àwọn ìṣúra tí a ti tò jọ tí a sì ti fi pamọ́ níbẹ̀.
BIBELI KIKA: Jòhánù 14:1-6.
ADURA: Baba ọ̀run ràn mí lọ́wọ́ láti rìn ní ọ̀nà òtítọ́ àti láti wà ní ipò òtítọ́. dari mi sinu awọn ilé to lẹwa. Ni orúkọ Jésù Kristi Ámín.