THE POWER OF TESTIMONY

THE SEED

“And they overcame him by the blood of the lamb, and by the word of their testimony…” Revelation 12:11

Testimonies are very powerful. Revelation 12:11 confirms that the devil can be overcome by the word of our testimony. Have you observed that those who frequently share testimonies always have new ones? This is because when you talk about what God has done in the past, He will be moved to do more. A testimony is a weapon of warfare. 2 Chronicles 20:5-7 shows this clearly. King Jehoshaphat knew how to give testimonies. Three different armies had gathered to destroy him, so he began to testify: God are you not the one who did this? Are you not the one who did that? God told him there was no need to fight the battle. Because he testified to the goodness of God in the life of the Israelites, Jehoshaphat and his people only had to sing and God destroyed this army before them. King David was another man who knew how to give testimonies. His testimonies are all over the book of Psalms. There is a lot to gain from sharing testimonies and a lot to lose from keeping God’s wondrous works to oneself. Have you been hiding your testimony? Why not start relaying your testimonies at every opportunity you have even if it is with just one person and see what God will do in your life? Share your testimony today and you will begin to experience more wondrous blessings from God.

BIBLE READINGS:  2 Chronicles 20:5-15

PRAYER: O Lord grant me grace to continually share my testimony to manifest your greater love towards me in Jesus’ name Amen

 

ÀGBÀRÁ IJẸRI

IRUGBIN NAA

Nwọn sí  ṣẹgun rẹ nítorí ẹjẹ ọ̀dọ̀ àgùntàn náa, ati nítorí ọ̀rọ̀ ẹ̀rí wọ́n… Ìfihàn 12:11.

Awọn ẹri jẹ ohùn alágbára pupọ. Ifihan 12:11 jẹri pe a le bori eṣu nipasẹ ọrọ ti ẹri. Èyí ni bi ẹ̀rí ṣe ṣe pataki to. Njẹ o ṣe akiyesi pe awọn ti o ma a njẹri nigba de ìgbà ni wọn máà n nì ẹ̀rí tuntun nigbagbogbo? Eyi jẹ pe  nigbati o ba sọrọ nipa ohùn tí Ọlọrun  ti ṣe tẹ́lẹ̀, a óò mu un láti ṣe púpọ̀ sí i, ijẹ́ri jẹ́ ohun ìjà ogún. Kíróníkà kejì orí 20 ẹsẹ 5 sí 7 fi èyí hàn ní kedere pé. Ọba Jèhóṣáfátì mọ̀ bí a ṣe ń jẹ́rìí.  Ẹgbẹ́ ọmọ ogun ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ mẹ́ta ní wọ́n kó ara jọ láti pa á run. O sí bẹ̀rẹ̀ sí ni jẹ́rìí:   Ọlọ́run àbí ìwọ kọ́ ni ó ṣe bayi? kì í ṣe Ìwọ ni o ṣe èyí ni? Ọlọ́run sọ fún pé ìwọ  ko ní ìjà li ọ̀ràn yí. Nítorí o jẹ́rìí si ojurere Ọlọ́run nínú ìgbésí ayé àwọn ọmọ Ísírẹ́lì. Jèhóṣáfátì ́àti àwọn ènìyàn rẹ̀ ni làti kọ orin si Ọlọ́run, O sì pa àwọn ọmọ ogun wọ̀nyí run níwájú wọn. Ọba Dáfídì tún jẹ́ ọkùnrin mìíràn tó mọ bí wọ́n ṣe ń ṣe ijẹri. Kò sí ohun tí Ọlọ́run ṣe fún Dáfídì tí ó dákẹ́ jẹ́ẹ́ lai jẹri si agbára Ọlọ́run. Èyí sì mú kí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣẹ́, àwọn  ogun wọn nígbà ọjọ́ rẹ̀.  awọn ẹ̀rí rẹ̀ wa nínú gbogbo Iwe Orin Dafidi. Ọpọlọpọ ere wa ninu ṣiṣẹ́ ijẹ́ri  si agbára Ọlọ́run, ati pípadànu pupọ wà  nípa pípa awọn iṣẹ iyanu Ọlọrun mọ, si ara rẹ. Njẹ o ti npa ẹri rẹ mọ́? Kini o le di ọ lọ́wọ́ lati ma  ṣé ijẹ́ri rẹ̀ pẹ̀lú àyè tí ó ba ni, bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ẹnìkan ki o sì wò ohun ti Ọlọrun yoo ṣe ninu igbesi aye rẹ. Pin ẹri rẹ loni, iwọ yíò bẹrẹ si ni ní iriri ọ̀pọ̀ iṣẹ iyanu lati ọdọ Ọlọrun.

 

BIBELI KIKA: 2 Kronika 20: 5-15

ADURA: Oluwa un mi ni oore-ọfẹ lati ma pin ẹri mi nigbagbogbo lati ṣafihan ifẹ nla rẹ si mi ni orúkọ Jesu Àmín

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *