THE SEED
“Then answered Jesus and said unto them, Verily, verily, I say unto you, the Son can do nothing of Himself, but what He seeth the Father do, for what things soever He doeth, these also doeth the Son likewise.”John 5:19
Total surrender in regards to following Christ means the complete submission of ourselves to him. It is submitting ourselves, our hearts, our bodies, our lives and our will to him without withholding anything. Jesus lived a life of continual surrender to the Father. True surrender happens when we completely trust God. Thereafter, God takes over all our troubles, and tribulations and delivers us from miseries. Surrender your heart to him, turn to him in prayer and give up your sins even those you do in secret then you will not be ashamed; you will be confident and fearless. If we can surrender to Him completely, It reduces anxiety and helps us regulate our emotions. Brethren, what our lord Jesus Christ requires of us is total submission to his will; he knows what our needs are and knows how to satisfy them. Give Him a chance to take over all things concerning you including your home, business, husbands, wives, children and your entire lives. Once you release all things totally, He is ever ready to take you up. You will then be assured of peace of mind, prosperity and long life. Surrendering yourself tomorrow might be too late.
BIBLE READINGS: John 5: 17-19
PRAYER: Father lord, I surrender my life to you today take over all things concerning me in Jesus’ Name. Amen
JI JỌ̀WỌ́ GBOGBO RẸ̀ PÁTÁPÁTÁ
IRUGBIN NAA
“Nigbana ní Jesu dáhùn, o si wi fún wọn pé, Lóòtọ́, lóòtọ́ ni mo wí fún yín, Ọmọ kó lè ṣe ohunkohun fún ará rẹ̀, bikoṣe ohùn tí ó ba rí pé Bàbá nṣe: wọnyi ni Ọmọ si ńṣe bẹ́ẹ̀ gẹgẹ.” Jòhánù 5:19
Ji jọ̀wọ́ gbogbo rẹ̀ lati tẹ́lẹ̀ Kristi túmọ̀ si, itẹriba pipe, ti ara wa fun u. Èyí tún pe fún ti tẹ ara wa bá, ọkan wa, ara wa, igbesi aye wa ati ifẹ wa fun u lai fi ohunkóhun pamọ́. Jesu gbe igbesi aye itẹriba nigbagbogbo fun baba Re. Itẹriba òotitọ yíò ṣẹlẹ nigbati a ba gbẹkẹle Ọlọrun patapata. Lẹhinna, Ọlọrun yió gba gbogbo wahala ati ipọnju wa, yio si gba wa lọwọ awọn ohun ijinlẹ ai f’oju rí. Jọwọ ọkan rẹ fún un, yipada si ọ̀dọ̀ Rẹ̀ ninu adura ki o si fi ẹṣẹ ikọkọ rẹ silẹ, lẹhinna ki yíò sí itiju mọ́; iwọ yió ni igboya ki yio si ìbẹ̀rù bí o bá lè jọ̀wọ́ ara rẹ̀ fún un pátápátá, yóò dín àníyàn kù, yió sì ràn wá lọ́wọ́ láti ṣe àkóso ìmọ̀lára wa.
Ará, ohun tí Olúwa wa Jésù Kristi ń béèrè lọ́wọ́ wa ni ìtẹríba pátápátá sí ìfẹ́ rẹ̀; Ó mọ ohun tí a nílò, ò sì mọ bí o ṣe lè tẹ́ wọn lọ́rùn. Fun un ni ààyè lati gba àkóso ohùn gbogbo nipa Ile rẹ, iṣowo, awọn ọkọ, awọn iyawo, awọn ọmọde ati gbogbo igbesi aye rẹ. Ni kete ti o ba jọ̀wọ́ ohun gbogbo patapata, O ti ṣetan nigbagbogbo lati ṣé adarí fún ọ. Lẹhinna iwọ yio ni idaniloju alafia ti ọkan, àṣeyọrí ati ọjọ́ gigun. Fi ara rẹ silẹ, ọla le pẹ̀ ju.
BIBELI KIKA: Johannu 5:17-19
ADURA: Oluwa àti bàbá wa, mo fi ẹ̀mí mi le ọ lọ́wọ́ loni, gba àkóso lori ohun gbogbo ni orukọ Jesu Amin.