VOICE OF THE LORD

THE SEED

The voice of the lord is powerful; the voice of the lord is full of majesty. Psalm 29:4 (KKV)

The voice of God is a communication from God to man, heard by man as a sound with no apparent physical source. There is no greater joy than hearing Jesus call. The voice of the lord is not only thundered in judgement but has also come to us in grace and truth in Jesus Christ. If God seems silent to you, be patient and keep listening. And don’t forget to pray – that two-way kind of prayer where we talk to God and then wait and listen for God to communicate with us and don’t give up. If we can accept for a moment that God’s voice can be heard today, what Might God be saying to you and me,  is this; accept the challenges I have laid before you and live your life in ways worthy of the calling to which God has called you. Life is full of challenges, mountains to climb, obstacles to leap over, races to run, and problems to overcome. We are called to accept these as best we can. Often we can not do them on our own but if we listen carefully, we will hear God’s voice saying ” I am with you always” Children, look upon Jesus himself as the perfect word of God and so, whatever he says or does we believe that it is God speaking through him and working through him. The voice of the Lord is powerful, the voice of the Lord is upon the waters, the God of glory thunders, the Lord is over many waters. Hallelujah!

BIBLE READINGS:  Psalm 29: 4-8

PRAYER: Lord Jesus, grant me the power to patiently listen to your voice. Amen

Saturday, September 28, 2024

OHÙN  OLÚWA

IRUGBIN NAA

“Ohùn Olùwà ni agbára; Ohùn Olùwà ni ọlanla.”  Psalmu 29:4

Ohùn Ọlọrun jẹ ibara ẹnisọrọ lati ọdọ Ọlọrun si eniyan; ti eniyan si ngbọ bi ohun, ti ko si ni orisun ibi ti o han gbangba tí ohùn náà tí ń jade wá. Kò si ayọ ti o tobi ju gbigbọ Jesu ti n pe. Ohun Oluwa kii ṣe àrá nikan nínú idajọ, ṣugbọn o  tun wa ninu Ore-ọfẹ àti ni otitọ ninu Jesu Kristi. Tí Ọlọrun ba dabi ẹni pe o dakẹ si ọ, ṣe suuru  ki o si tẹ̀ síwájú láti máà gbọ. Kí o maṣe gbagbe lati gbadura,  iru adura ti o pín si ọna meji ni ibí tí a ti nba Ọlọrun sọrọ, ati lẹhinna duro ki o gbọ  Ọlọrun lati ba ọ sọrọ ati  maṣe jẹ́kí o sún ọ. Tí a ba le gba ni iṣẹju kan pe ohun Ọlọrun le di gbigbọ loni, kíni ohun ti Ọlọrun le maa sọ fun iwọ ati èmi ni eyi;  gba awọn ipenija ti mo ti gbe siwaju rẹ, òkè lati gùn, àwọn ìṣòro láti re kọjá, ire ìje lati sá, ati awọn ìṣòro láti  borí. A pé wa láti gbá awọn  ipenija wọ̀nyí pẹ̀lú ipá wa. Nígbà miran a ko lè dójú kọ wọ́n fún ra wa ṣugbọn ti a bá tẹti sílẹ̀ dáradára ao gbọ ohùn ̀ Ọlọ́run eyi ti o wípé “Mo wa pẹ̀lú yin nigba gbogbo.” Ẹyin ọmọde ẹ máa wo Jesu funrarẹ bi ọ̀rọ̀ Ọlọ́run pipe, ati pe ohunkohun ti o ba sọ tabi ti o ṣé gbàgbọ́ wipe Ọlọ́run nsọrọ nípasẹ̀ Rẹ̀ ti o si n ṣíṣe nípasẹ̀ Rẹ̀. Ohun Oluwa ni àgbàrá, ohun Oluwa wa lori awọn omi,  ogo Ọlọ́run  sàn ãra, Oluwa wa lori awọn omi pupọ Halleluyah!

BIBELI KIKA:  Psalmu 29: 4-8

ADURA: Jesu Oluwa, fun mi ni agbara lati fi suuru gbọ́ ohun Rẹ̀. Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *