FRUITFULNESS CAN BE A TWO WAY BLESSING

THE SEED

But blessed is the one who trusts in the LORD, whose confidence is in Him. They will be like a tree planted by the water… Jeremiah 17: 7-8 NIV

A Pastor recounted how she was led to a car wash in London at the prompt of the Holy Spirit. The Spirit told her to speak Swahili (a Kenyan language) to the attendant, she initially felt reluctant, but she realised quickly that once she decided to yield to the voice from the beginning, she needed to commit the talk to God’s hands as she was not that fluent in Swahili. Yes, she managed to reconnect the young man to God. He was a Christian who left the faith because he emigrated to the UK. The texts discuss various benefits of trusting in the Lord, the examination of the heart and mind, the consequences of forsaking the Lord, and the importance of the Lord as a source of hope and living water.  When a tree is deeply rooted, the leaves are not bothered by heat or drought; therefore, there is an assurance of continuous fruitfulness. The young man, because of circumstances mainly reasons of survival forsook the faith, but the fruitfulness of someone made him see sense and reconnect to the spring of living water. Being fruitful makes you a blessing to other people. The other way is that you also receive blessings from the Lord, He will readily supply all your needs from the depth of His storehouse. Be saved and lead others to salvation.

BIBLE READINGS:  Jeremiah 17: 7-13

PRAYER: Lord, let me yield to your call to bless others and for me to be blessed by you.

 

SISO ESO LE JE IBUKUN ONA MEJI

IRUGBIN NAA

Ṣugbọn ibukun ni fun ẹniti o gbẹkẹle Oluwa, ẹniti o gbẹkẹle e. Wọn yóò dàbí igi tí a gbìn se bàá omi tí ó ta gbòǹgbò rẹ̀ segbe odò… Jeremáyà 17:7-8

Olusoagutan kan sọ bi wọn ṣe mu u lọ si ibi ti a ti n fo ọkọ ayọkẹlẹ kan ni Ilu Lọndọnu nipasẹ Ẹmi Mimọ. Ẹ̀mí náà sọ fún un pé kó máa sọ ede Swahili (èdè Keńyà) fún eni ti I wa ni ibi ise naa. O koko lora, àmo ó wá rí i pé gbàrà tí òun bá pinnu láti fara mo ohùn náa, òun gbodọ̀ Fi Oro na sí owo Ọlorun toripe ko le so ede Swahili naa daradara. Bẹẹni, o ṣakoso lati tun ọdọ ọdọmọkunrin naa pọ mọ Ọlọrun. O jẹ Kristiani ti o fi igbagbọ silẹ nitori pe o lọ si UK. Àwọn ẹsẹ Ìwé Mímo náà sọ̀rọ̀ lórí onírúurú àǹfààní tó wà nínú gbígbe kẹ̀ lé Olúwa, àyẹ̀wò ọkàn àti èrò inú, àbájáde kíkọ Jèhófà tì, àti ìje pàtàkì Olúwa gege bí orísun ìrètí àti omi ìyè. Nigbati igi kan ba ti Fi gbongbo re mulẹ, awọn ewe re ki yio gbe nígbà ooru tabi ọgbẹle. Nitorina,idaniloju siso eso nígbà gbogbo wa fun iru igi bee. Ọdọmọkunrin naa, nitori awọn idojuko ti o ni fi igbagbọ silẹ, ṣugbọn eso ẹnikan jẹ ki o ni oye ki o tun sopọ mọ orisun omi iye. Siso eso yio mu ki o jẹ ibukun fun awọn eniyan miiran. Onà Miran nipe, iwo yio ri ibukun gba látodo Oluwa. Yio pese fun gbogbo aini re latorisun ibukun re. Di eni igbala, ki o si gba ẹlòmíràn la.

BIBELI KIKA: Jeremáyà 17:7-13

ADURA: Oluwa, jẹ ki n faramọ ipe rẹ lati bukun awọn ẹlomiran ati fun mi lati jẹ ibukun nipasẹ rẹ.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *