THE SEED
”Were they ashamed when they committed abomination? No, they were not at all ashamed; they did not know how to blush. Therefore they shall fall among the fallen; when I punish them, they shall be overthrown, says the Lord.“ Jeremiah 8:12
Playing ignorant with sin doesn’t work! There is no doubt that our Heavenly Father is a merciful God who knows and understands our frailty but He is also a disciplinarian who does not condole sin. It’s wrong to rob our weakness on God’s face for an excuse not to ask for forgiveness when we go astray. Unfortunately, We can’t decide for God how to deal with our wrongdoings. It is very wrong to say things like ‘He knows that I’m human’ of cause, God created us and understands the human nature of sin, which is why He has made the provision for us to repent and ask for forgiveness when we fall short of His glory. Failure to comply with this instruction would invite God’s punishment on us. The opening scripture is the word of God to the Israelites who were found guilty of this offence. God is not and can’t be happy with anyone who refuses to ask for the forgiveness of their sins.
BIBLE READINGS: James 4:7-10
PRAYER: Lord, I’m sorry for playing ignorance instead of confessing my sins. I wholeheartedly ask for your forgiveness today, kindly forgive me of all my wrongs in Jesus’ name. Amen
MAṢE ÀRÉKÉREKÈ PẸ̀LÚ ỌLỌ́RUN, RONÚ PÌWÀDA.
IRUGBIN NAA
Ǹjẹ́ wọ́n tijú nítori wọ́n ṣé ohùn ìríra, síbẹ̀ wọ́n kó tijú, bẹni òórù ìtìjú kó mú wọ́n, nítorí náà ni wọ́n o ṣé ṣubú, laarin awọn ti o ṣubú; nígbà ìbẹwò wọ́n, a ó sí wó wọ́n lulẹ, lí Olúwa wi. Jeremáyà 8:12
Nípa ìhùwàsí aibikita pẹlu ẹṣẹ ko ṣiṣẹ! Kò sí iyèméjì pé bàbá wa ọ̀run jẹ́ Ọlọ́run aláàánú tí ó mọ̀, tí ó sì lóye àìlera wa, ṣùgbọ́n ó tún jẹ́ olùbáwí tí kì í faramo ẹ̀ṣẹ̀. O jẹ aṣiṣe lati fí ailera wa han ni oju Ọlọrun, awawi ni o di jẹ́ lati ma beere fun idariji nibiti a ti ṣina. Ó ṣeni làánú, pé a ko le ba Ọlọ́run dá mọran bi yio ṣe le bá wa wí lórí awọn aitọ wa. O jẹ aṣiṣe pupọ lati sọ awọn nkan bii O mọ pe eniyan ni mi, Ọlọrun lo ṣe ẹda wa o si loye Ìṣẹ̀dá eniyan nipa ti ẹṣẹ; ti o jẹ ère ìdí ti o fi ṣe ipese fun wa lati ronupiwada ati tọrọ idariji nigbati a ba kuna ogo Rẹ. . Ikuna lati wa ni ibamu pẹlu ilana yii yoo pe ijiya Ọlọrun wa sori wa. Ọ̀rọ̀ inú iwe-mimọ tí akọkọ jẹ́ ọrọ Ọlọrun si awọn ọmọ Israeli ti wọn jẹbi nínú ẹṣẹ yí. Inú Ọlọrun ko le dun, kò sí lé ni idunnu pẹlu ẹnikẹni ti o kọ lati beere fun idariji ẹ̀ṣẹ̀ wọ́n.
BIBELI KIKA: Jakobu 4: 7-10
ADURA: Oluwa mo tọrọ aforiji fun aṣiṣẹ aimokan. Mo fi gbogbo ọkàn tọrọ idariji loni, jọ̀wọ́ dariji mi, fun gbogbo àṣìṣe mi lórúkọ Jesu.