THE SEED
”Your steadfast love, O Lord, extends to the heavens, your faithfulness to the clouds.“ Psalm 6:5 ESV
As we approach the close of this year, it’s proper to reflect on the faithfulness of God in our journey. For some moment today, let’s just go through memory lane in our minds to visualise the mighty deeds of the Lord in giving us victory over sin, victory over life challenges and attacks of the enemy, for His divine provisions and for promotions and breakthroughs. In truth, we can boldly say that God’s faithfulness is boundless. His faithfulness extends to the heavens, yes it does! God’s faithfulness comes with different newness every day; how awesome you are oh God! Despite our shortcomings and unwillingness at times, He never changes His mind on us, the thought that God is with us in the journey has made a whole lot of positive difference to how we navigate through it all. Even though the enemy had planned failure, untimely death, shame and unfruitfulness for us in the year, the faithfulness of God has turned our cry to a shout of joy and all unfruitfulness into rewarding harvest. God turned all evil plans meant to hurt us to stepping stones to take us to fulfil His beautiful plans for our life. We have encountered the God that abounds in steadfast love and faithfulness. Let us not lose our focus on Him as we depend on Him and take refuge in the shadow of His wings.
BIBLE READINGS: Psalm 6:5-10
PRAYER: Lord, in your faithfulness, continue to keep me under the shadow of your wings all the days of my life in Jesus’ name. Amen
AFIHAN NINU OTITO OLORUN
IRUGBIN NAA
Iduro sinsin Ife re, iwo Oluwa, o ga de orun, otito re ga de awosanmo Psalm 36: 5
Bi a se nsumo ipari odun, o se Pataki lati se afihan ninu Igbagbo Olorun ninu irinajo wa yii. Fun asiko die, e je ki a wo ibi ti ati nbo ninu okan wa, lati mo riri ise Olorun ninu aye wa, nipa fifun wa ni isegun lori lori ese, isegun lori ipenija ati idojuko ota. Fun ipese re lojoojumo lori aye wa, fun igbega ati aseyori ninu aye wa ati ni aye ebi wa. Nitooto, a le fi igboya so wipe Olotito ni Oluwa. Iwe Oni saamu so fun wa ni ese ti o bere wipe otito re de orun, beeni. Otito Olorun je otun fun w ani ojojumo. Bawo ni o se tobi to Olorun! Pelu gbogbo aisedede wa, ko yi okan re kuro lodo wa, ero wipe Olorun wa nipa ti wa ninu irinajo yii, o mu iyipada rere fun wa. Botile jepe ipinu ota ti ye lori wa, iku ojiji, itiju ati aileso ti kuro ni aye wa. Olorun ti so ekun wa di ayo, ati aileso wa di ikore nla. Gbogbo ipinu Ota ni Olorun ti so di okuta ategun fun wa, lati jeki ipinu re wa si imuse ninun aye wa. Ati se alabapade Olorun ife ati olotito ninu aye wa. E ma jeki a so ireti nu ninu Olorun, gegebi a se gbeke wa le ti a si sa si abe abo re.
BIBELI KIKA: Psalm 36:5–10
ADURA: Oluwa, ninu otito re, tu bo ma pami mo ni abe iye apa re titi ojo aye mi ni oruko Jesus, Amin.