PUT YOUR TRUST IN GOD
THE SEED
“Trust in the LORD with all thine heart; and lean not unto Thine own understanding” Proverb 3:5 KJV
Trusting God simply means believing in Him in every situation, when you trust God, you know He won’t fail you no matter the circumstances you are going through, He will always deliver you and fight your battle. King David trusted in God when enemies came to capture his people and their belongings. The first thing he did was ask God, should I go after them? Will I win this battle? He trusted God to a level that he prioritised Him in all of his decisions. Whatever steps we want to take in life, we should trust God for it and not lean on our understanding, believing Him to solve every one of our problems for us. When He tells us to wait while others are running, we should still trust in Him, Even when He instructs us to do what does not align with our will we should succumb and trust Him because His ways are not our ways and neither His thoughts our thoughts, it surpasses human knowledge. As you step out today, trust God for every decision of your life.
BIBLE READING: I Samuel 30:1-8
PRAYER: My God, help me to trust you in all areas of my life, so that I won’t lean on my understanding, Amen.
FI ÌGBẸ́KẸ̀LÉ RẸ SÍNÚ ỌLỌ́RUN
IRUGBIN NAA
“Fi gbogbo àyà rẹ gbẹ́kẹ̀le Olúwa; ma si ṣé tẹ̀ sí ìmọ̀ ara rẹ”. Owe 3:5
Gbẹkẹle Ọlọrun nìkan tumọ si gbigbagbọ ninu Rẹ̀ ni gbogbo ipòkipo, nigbati o ba gbẹkẹle Ọlọ́run, o mọ pe Oun kí yíò já ọ kulẹ̀, bi o ti wu ki ohun tí ó ńlá kọjá ṣé lé tó yíò gba ọ nigbagbogbo yíò sí ja ogun rẹ. Ọba Dafidi gbẹkẹle Ọlọrun nigbati àwọn ọ̀tá wa láti kó àwọn èniyàn rẹ̀ pẹ̀lú àwọn ohun ini wọ́n lọ. Ohun akọkọ ti o ṣe ni pé o beere lọwọ Ọlọrun pe, ṣé mo le lépa wọn bi? Ṣe emi yíò ṣẹ ogun yii? O gbẹkẹle Ọlọrun de ipele ti o ṣe pataki fun un ninu gbogbo awọn ipinnu rẹ. Àwọn igbesẹ tí o wù kí a fẹ lati gbe ni igbesi aye, a ni lati gbẹkẹle Ọlọrun fun irú rẹ, ki má tẹ̀ sí ìmọ̀ tí ara wa; ki a gbẹkẹle pe yíò yanjú ìṣòro wa fún wa ní ọ̀kan kan. Nigba ti o ba sọ fun wa lati duro nigba ti awọn miiran nsa ère , a gbọdọ gbẹkẹle e. Paapaa nigba ti o ba kọ wa lati ṣe ohun ti ko wa ni ibamu pẹlu ifẹ wa, a gbọdọ tẹriba ki a gbẹkẹle e nitori awọn ọna Rẹ̀ kii ṣe ọna wa, ati pe awọn ero Rẹ̀ kii ṣe ero wa; ó ju ìmọ̀ ènìyàn lọ. Bí ó ti ṣe njade ní ọjọ́ òní gbẹ́kẹ̀le Ọlọ́run fún gbogbo ìpinnu tí ó ni fún ayé rẹ.
BIBELI KIKA: 1Samueli 30:1-8
ADURA: Ọlọ́run mí, ran mi lọ́wọ́ lati gbẹkẹle Ọ nigbogbo, ní ọ̀nà ayé mí, kí èmi má bàa tẹ̀ sí ọ̀nà ara mi. Amin.