DEEPER INTIMACY WITH GOD THE SEED

DEEPER INTIMACY WITH GOD THE SEED
“Create in me a clean heart, O God, and renew a right spirit within me.” – Psalm 51:10 (KJV)

Just as a child grows through milestones, our relationship with God must mature. At the early stages, we often focus on material needs. But as we grow, we yearn for deeper intimacy with God. David longed for a clean heart and a right spirit—a desire for God Himself above things. There are many spirits at work, but only the Spirit of God enables us to please Him and live above the flesh. This is the deeper walk God desires for His children: consistent growth in character, intimacy, and holiness.

BIBLE READINGS: Psalm 51:1–12 (KJV)
PRAYER: Father, purge me and fill me with Your Holy Spirit so I may live in deeper intimacy with You. Amen.

Ì B Á Ṣ E P Ò T I ́ O ́ J I N L Ẹ ̀ P Ẹ̀ L Ú ỌLỌ́RUN.
IRUGBIN NAA

Dá ọkàn mímọ́ sí inú mi, Ọlọ́run, kí o sì tún ẹ̀mí dídúró ṣinṣin ṣe sínú mi. Psalmu 51:10.

Gẹgẹ ́bí ọmọde ṣe ndagbà ni ẹsẹesẹ, ìbáṣepọ̀ wa pẹlu Ọlọ́run gbọ́dọ̀ máa ni idàgbàsókè. Ni Ìbẹ̀rẹ̀ ayé wa, a máa n ní àfojúsùn lórí ohun tí a nílò nipa ti ara. Ṣùgbọ́n bí a ṣe ń dàgbà, a ńla kàkà fún ìbárẹ́ tímọ́tímọ́ pẹ̀lú Ọlọ́run. Dáfídì pongbẹ fún ọkàn mímọ́ àti ọkàn dídúró ṣinṣin —ìfẹ́ fún Ọlọ́run fúnra rẹ̀, ju àwọn nǹkan míràn lọ. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀mí ló ń ṣiṣẹ́, ṣùgbọ́n Ẹ̀mí Ọlọ́run nìkan li o ńmú wa jẹ́ ki a lè tẹ́ ẹ lọ́rùn, ki á sì máa gbé e ga ju ara lọ. Èyí ni ibarinpọ ti o jinlẹ̀, tí Ọlọ́run ń fẹ́ fún àwọn ọmọ Rẹ̀: ìdàgbà sókè déédéé nínú ìwà, ìbáṣèpọ, àti ìwà mímọ́.

BIBELI KIKA: Sáàmù 51:1-12 (KJV)
ADURA: Baba, wẹ mi ki o si fi Ẹmi Mimọ Rẹ kun mi, ki n le gbe ni ìrẹ́pọ̀ ti o jinlẹ̀ pẹlu Rẹ. Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *