REMEMBER HIS FAITHFULNESS

THE SEED
“Bless the Lord, O my soul, and forget not all his benefits.” — Psalm 103:2 KJV
Forgetting God’s goodness makes us vulnerable to fear and doubt. David remembered God’s faithfulness when facing Goliath, and it strengthened his faith.
Israel, on the other hand, often forgot God’s works and perished in the wilderness. Remembering past testimonies fuels our faith and empowers us to face future battles with confidence.
BIBLE READINGS: 1 Samuel 17:32–37
PRAYER: Lord, help me to always remember Your goodness and faithfulness in my life. Amen.

RANTI OTITỌ RẸ̀
IRUGBIN NAA
“Fi ìbùkún fún Olúwa, ìwọ ọkàn mí, má sí ṣé gbàgbé gbogbo oore Rẹ̀ “. Psalmu 103:2.

Gbí gbàgbé oore Ọlọ́run máa ń jẹ́ kí a wa nínú ewu ìbẹ̀rù àti iyèméjì. Dáfídì rántí lotítọ́ Ọlọ́run nígbà tó dojú kọ Gòliátì, ó sì fún ìgbàgbọ́ rẹ̀ lókun. Ní idakeji ẹ̀wẹ̀, Ísrẹ́lì máa ń gbàgbé àwọn iṣẹ́ Ọlọ́run, wọ́n sì ṣègbé nínú aginjù. Rírántí àwọn ẹ̀rí tí ó ti kọjá maa nfun ìgbàgbọ́ lágbára láti dojú kọ àwọn ogun ọjọ́ iwájú pẹ̀lú ìgboyà.

BIBELI KIKA: 1 Sámúẹ́lì 17:32–37

ADURA: Oluwa, ran mi lowo lati ma a ranti
oore ati òtítọ́ Rẹ nigba gbogbo ninu aye mi. Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *