FOLLOW GOD’S COUNSEL

FOLLOW GOD’S COUNSEL

THE SEED

“Men, I see that our voyage from here on will be dangerous; there will be great damage to the cargo and to the ship, and loss of life as well. But the army officer was convinced by what the captain and owner of the ship said…” — Acts 27:10–11 GNB

The counsel of God often appears contrary to common sense or human logic. Human wisdom relies on past experiences or conclusions that may not always be accurate. But God’s counsel is anchored in what is to come—truth that only He knows. Paul warned of danger, but the people trusted their own reasoning and paid the price. When God speaks, obedience secures our safety. Trusting His counsel above human wisdom protects us from the shipwrecks of life.

BIBLE READINGS: Acts 27:9–21

PRAYER: Heavenly Father, regardless of my understanding or past experiences, help me to always follow Your counsel. Amen.

 

T Ẹ́  L Ẹ̀  I M Ọ R A N  Ọ L Ọ́ R U N

IRUGBIN NAA

“Ó sì wí fún wọn pé, Alagba, mo woye ìṣíkọ̀ yí ní ewu àti òfò púpọ̀, kí ìṣe kìkì tí ẹrù àti tí ọkọ̀ , ṣùgbọ́ n ti ẹ̀ mí wa pẹ̀lú. Ṣùgbọ́ n Balógun ọ̀run gba tí olórí ọkọ̀ àti ti ọlọkọ gbọ, ju ohun wón ̣ ni tí Paulu wí lọ”. IṢẸ́ ÀWỌN ÀPỌ́ SÍTÉLÌ 27:10-11

Ìmọ̀ ràn Ọlọ́ run sábà máa ń fara hàn bí ìlòdì sí ọgbọ́ n orí, tàbí ọgbọ́ n ènìyàn. Ọgbọ́ n ènìyàn da lé ori àwọn ìrírí tí ó ti kọjá tàbí àwọn tí a tí sọ parí, tí kó kùn ojúòṣùwòṇ . Ṣùgbọ́ n ìmọ̀ ràn Ọlọ́ run ni ìfi- ẹsẹ -mulẹ nínú ohun tí ń bọ̀ —òtítọ́ tí Òun nìkan ṣoṣo mọ̀. Pọọlù kìlọ nípa ewu, ṣùgbọn àwọn ènìyàn ́̀̀́ náà gbẹ́kẹ̀ lé ìrònú ara wọn, wọ́n sì koju àbájáde ìdààmú tí o ti ẹ̀hìn rẹ ̀jáde. Nígbà tí Ọlọ́ run bá sọ̀ rọ̀ , ìgbọràn máa ń dáàbò bò wá. Gbígbẹ́kẹ̀lé ìmọ̀ràn Rẹ̀ ju ọgbọ́n ènìyàn lọ ń dáàbò bò wá kúrò lọ́wọ́ ìjì ìparun inú ayé.

BIBELI KIKA: Ìṣe 27:9–21.

ADURA: Baba wa Ọrun, botiwu ki oye mi tabi awọn iriri ti o ti kọja ri, ràn mí lọwọ lati tẹle imọran Rẹ nigbagbogbo. Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *