GOD DELIGHTS IN YOUR PROSPERITY

GOD DELIGHTS IN YOUR PROSPERITY

THE SEED

Let them shout for joy and be glad, Who favor my righteous cause; And let them say continually, “Let the Lord be magnified, Who has pleasure in the prosperity of His servant.” — Psalm 35:27 KJV

God delights in seeing His children prosper. True kingdom prosperity is not based on background, profession, or human connection but on covenant alignment with God’s Word. When you discover and act on God’s Word regarding prosperity, you operate with divine wisdom, and blessings follow. Prosperity is not luck or chance — it is the result of walking in God’s light. If your light has come, your rising will manifest.

BIBLE READINGS: Deuteronomy 28:1–10

PRAYER: O Lord, prosper me and let my life glorify You. Amen.

 

ỌLỌ́ RUN NÍ INÚ-DÍDÙN SÍ ÌṢERERE RẸ

IRUGBIN NAA

Jẹ́ kí àwọn tí ó fẹ́ ìdáláre mi fò fún ayọ̀ àti ìdùnnú; kí wọn máa sọ ọ́ títí lọ, “Pé gbígbéga ni Olúwa, sí àlàáfíà ìránṣẹ́ rẹ̀.” Psalmu 35:27.

Inú Ọlọ́run maa ndùn láti rí ìṣerere àwọn ọmọ Rẹ̀. Ìṣerere ijọba ọ̀run ko da lori ibi ti a bi o si, tabi iṣẹ ti o yan laayo, tabi eniyan ti o mọ, ṣugbọn lori ibamu majẹmu pẹlu Ọrọ Ọlọrun. Nigbati o ba ṣawari ti o si ṣiṣẹ lori Ọrọ Ọlọrun nipa ìṣerere, iwọ nṣiṣẹ pẹlu ọgbọn atoke wa, ibukun yio sí tẹle. Ìṣeréré kiiṣesábàbí,tàbíọ̀nàtóyọsíọlojiji-ojẹ àbájáde rìnrìn nínú imọlẹ Ọlọ́ run.Ti imole re ba de, igbega re yoo farahan.

BIBELI KIKA: DEUTERONOMI 28:1- 10

ADURA: Olúwa, mu mi se réré ki o si jẹ́kí aye mi kí o yin Ọ logo. Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *