TRANSFORMED FROM WITHIN
THE SEED
“Do not conform yourselves to the standards of this world, but let God transform you inwardly by a complete change of your mind.” — Romans 12:2 GNB
Simon the Sorcerer believed the gospel but still held onto his old desires for recognition. Transformation is not automatic at salvation — it’s a deliberate, ongoing process. Your spirit is born again, but your mind must be renewed. God will not force transformation on you; you must allow Him to reshape your thinking through prayer, Word study, and fellowship. Real change begins within, and only a transformed mind can fully reflect Christ.
BIBLE READINGS: Romans 12:1–2; Acts 8:9–24
PRAYER: Heavenly Father, I yield my mind to Your transforming power. Renew my thoughts to align with Your will. Amen.
ÌYÍPADÀ ỌKÀN ATINUWA
IRUGBIN NAA
“Kíẹmásìṣédáarayínpọ̀ mọ́ ayéyi: ṣùgbón ̣ kí ẹ parada láti dí tuntun ní ìrò inú yin, kí ẹ̀yìn kí ó lé rí ìdí ifẹ Ọlọrun, tí ó dára tí ósìṣeìtéẉ óg̣ bà,tíósìpe.”ROMU12:2
Símónì onídán gba ihinrere gbọ ṣugbọn okan re rò ̣̣ mó ̣ ife atijo to ni fun òkìkí. Iyipada kii ṣe ohun ti o n ṣẹlẹ̀ lakotan nigba tiagbawala–ojeohuntiyoomatesiwaju. Ẹmi rẹ ti di atunbi, ṣugbọn ọkan rẹ gbọdọ di tuntun. Ọlọ́run ki yíò fi ipá yi ọ pada; o gbọdọ fí àyè gbà a láti tun ero rẹ ṣe nipasẹ adura, ẹkọ Ọrọ, ati ìdápọ. Iyipada tooto bẹrẹ lati inu, ati pe iyipada ọkan nìkan lo le ṣe afihan Kristi ni kikun.
BIBELI KIKA: RÓÒMÙ 12:1–2; ÌṢE ÀWỌN ÀPỌ́ SÍTÉLÌ 8:9–24.
ADURA: Bàbá wa Ọrun, Mo fi ọkan mi fun agbara iyipada Rẹ. Tun awọn ero mi ṣe lati ni ibamu pẹlu ifẹ Rẹ. Amin