YOUR TRUE IDENTITY IN CHRIST
THE SEED
“A good tree can’t produce bad fruit, and a bad tree can’t produce good fruit. A tree is identified by its fruit.” — Luke 6:43–44 NLT
As children of God, our lifestyle should clearly reflect our spiritual identity. The way we speak, behave, and present ourselves should reveal Christ in us. Our identity is not hidden—it is seen through our fruit. Who you are in Christ is your greatest testimony. When your fruit aligns with His Word, your life silently preaches the gospel to everyone around you. Your identity is not a title; it’s a daily expression of His nature in you. We must live deliberately, ensuring that our words and actions align with Christ’s standard. A good tree cannot produce bad fruit.
BIBLEREADINGS: Galatians5:16–26 PRAYER: Father, help me reflect my true
identity in Christ in every area of my life. Amen.
OTITO IDANIMO RE NINU KRISTI
IRUGBIN NAA
“Nítorí igi rere kì í so èso búburú; bẹ́ẹ̀ ni igi búburú kì í so èso rere. Luku 6:43
Gegebi omo Olorun, igbe aye wa gbodo s’afihan idanimo igbagbo wa. Isorosi wa, ihuwasi àti ifarahan wa gbodo fi Kristi ti o n gbe inu wa han. Eri idanimo wa kò f’ara sin- o f’ara han nipa eso wa.
EnitiojeninuKristinieriretiotobiju! Nigbati eso re ba wa ni ibamu pelu Oro Re, aye re yio rora maa waasun ìhìnrere si gbogbo enia ni agbegbe re. Idanimo re kii se oye ti o je, sugbon, o je ifarahan iwa bí Olorun inu re. A gbodo moomo gbe igbe aye ti o ba igbe aye Kristi mu. Igi rere kii so eso buburu.
BIBELI KIKA: Galatia 5:16-25
ADURA: Baba, ran mi lowo lati le maa fi eri idanimo mi ninu Kristi han ni gbogbo ojo aye mi.