AMBASSADORS FOR CHRIST

AMBASSADORS FOR CHRIST
THE SEED
“Now then we are ambassadors for Christ, as though God did beseech you by us: we pray you in Christ’s stead, be ye reconciled to God.” — 2 Corinthians 5:20 KJV
Every believer is called to represent Christ on earth. As His ambassadors, we are not just redeemed individuals but co-heirs with Christ, entrusted with the responsibility of proclaiming His excellencies. An ambassador carries the voice and authority of the kingdom they represent. You are God’s voice to your generation, a vessel through which His love, truth, and power can flow. Your daily actions and words preach a message, even when you don’t speak. Being an ambassador is a high privilege but also a serious responsibility. God expects us to live in a way that draws others to Him and reflects the glory of His Kingdom.
BIBLE READINGS: 1 Peter 2:9–12 PRAYER: O Lord, I choose to be Your
ambassador till the close of day. Amen.

 

ÀWON IKÒ FÚN KRISTI

IRUGBIN NAA

Nítorí náà àwa ni ikọ̀ fún Kristi, bí ẹni pé Ọlọ́runńtiọ̀dọ̀waṣìpẹ̀fúnyín:àwańbẹ̀yín ní ipò Kristi, “Ẹ bá Ọlọ́run làjà,”. Korinti Keji 5:20

Gbogbo onigbagbo ni a pe lati je iko ̣ tabi ̀ asoju fún Kristi ní ayé. Gege bí iko Re, awa kii se eni irapada lasan sugbon ajumojogun pelu Kristi ti a fun lágbára lati polongo ola nla Re. Iko ni ohùn àti àsẹ ̣Orile Ede ti won ba n s’oju fun. Iwo ni ohun Olórun si iran re, ohun elo ti ife Re, otito ati agbara Re n gba sàn jade. Ise ati oṛ o ̣re ̣n waasun Re, koda bí o kò tile soro. Jije iko je anfaani nla sugbon o
pe fun ojuse gidigidi. Olorun n reti wa lati gbe lona ti o fa awon omiran si odo Re ti osi fi ogo Re han.

BIBELI KIKA: Peteru Kinni, 2:9-12.

ADURA: Oluwa, mo yan lati je iko Re titi di ojo ale. Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *