GUARD THE TEMPLE WITHIN

GUARD THE TEMPLE WITHIN

THE SEED

“If any man defile the temple of God, him shall God destroy; for the temple of God is holy, which temple ye are.” — 1 Corinthians 3:17 KJV

The heart is the holiest temple God desires to dwell in. Even the smallest compromise can give the enemy a foothold. We must keep our hearts pure and wholly surrendered to Christ. A guarded heart is a powerful weapon. When God reigns at the center of your life, sin loses its grip and your inner altar becomes a place of strength, worship, and divine encounter. Protect it with prayer, the Word, and obedience. The love of God has been poured into our hearts through the Holy Spirit. When our hearts are yielded, His presence fills our inner temple, and we ascend spiritually through daily communion with Him.

BIBLE READINGS: Romans 5:1–5 PRAYER: Lord, come and take Your rightful place in my heart. Amen.

SỌ́ṬÉMPÍLÌ RE

IRUGBIN NAA

Bí ẹnikẹ́ni bá ba tẹmpili Ọlọ́run jẹ́, òun ni Ọlọ́run yóò parun; nítorí pé mímọ́ ni tẹmpili Ọlọ́run, èyí tí ẹ̀yin jẹ́. Korinti Kinni 3: 17

Okan ni tempili mimo julo ti Olórun n fe lati gbe. Igbojege kekere lasan le f’aye gba ota. Agbodojekiokanwawanipipe,kiasi jowo re fún Kristi. Okan ti a pamo je ohun elo alagbara. Ti Olórun ba j’oba ni ookan ayere,eseafiosile,pelupelu;pep̣eịnurea wa di ibi agbara, iyin, ati ikorita emi. Dá à bò bò ó pelu adura, Oro Olorun, pelu igboran. A ti tu ife Olórun si okan wa nipase Emi Mimo. Ti a ba ti yonda okan wa, iwalaaye Re a kun tempili wa, a o wa g’oke ni ipele emi nipase ibasepo wa pelu Re lojoojumo.

BIBELI KIKA: Romanu 5:1-5
ADURA: Oluwa, wá lati gba ààyè ninu okan mi. Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *