DON’T ABUSE GRACE

THE SEED

“Do not fear, for I have redeemed you; I have summoned you by name; you are mine.” — Isaiah 43:1 NIV

Grace is not a license to sin. God’s love and redemption should lead us to reverence, not pride or complacency. Many carry wrong attitudes—refusing repentance and taking God’s grace for granted. When we truly understand the weight of the price Jesus paid, grace becomes a call to deeper devotion, not a free pass for careless living. Genuine gratitude for redemption produces humility, repentance, and a transformed heart that seeks to honour God daily. True grace calls us to repentance, humility, and holy living. Let your attitude reflect gratitude for His redemption.

BIBLEREADINGS: Romans6:1–4 PRAYER: Lord, teach me to walk in

humility and not take Your grace for granted. Amen.

MÁṢE ṢI OORE ÒF̣ÉḶÒ

IRUGBIN NAA

“Má bẹ̀rù, nítorí Èmi ti dá ọ nídè; Èmi ti pè ọ́ ní orúkọ; tèmi ni ìwọ ṣe. Isaiah 43:1

Oore ofe ko gba wa laye lati sè.̣ Ife Olórun àti irapada yio mu wa wo ̣ ipele ìbòẉ ò,̣ kii se ìgbéraga tabi aibikita. Opo lo gbe iwa ti kò ye,won kọ ironupiwada won si n si oore-ofe Olorun lo. Nigba ti a ba mo riri iye ti Jésù san, oore-ofe yio wa di ipe si if’ara eni ji, kò ni je ipe fún igbe aye aibikita. Imoore otito fun irapada maa n fa irele, ironupiwada ati iyipada okan eyi ti yio mu wa bowo fun Olorun lojoojumo. Oore ofe otito pe wa si ironupiwada, irele àti igbe aye iwa mimo. Je ki iwa re fi imoore re han fun ise irapada Re.

BIBELI KIKA: Romu 6:1-4
ADURA: Oluwa, ko mi lati rin ninu irele lai sị oore ofe Re lò. Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *