THE SEED
“Then God remembered Noah, and every living thing, and all the animals that were with him in the ark.” – Genesis 8:1 (NKJV)
When God “remembers,” it does not mean He forgets. It means He chooses to act on your behalf at His appointed time. Noah waited in the ark while the flood covered the earth. It must have felt long, silent, and lonely—but God remembered him.
In the same way, God will remember you in your season of waiting. He will remember your prayers, your tears, your faithfulness, and your sacrifices. When God remembers, doors open, promises are fulfilled, and testimonies are born.
Hold on in faith. Your season of remembrance is coming.
BIBLE READINGS: Genesis 8:1–12 (KJV)
PRAYER: Father, t hank You for remembering me. Let my waiting season end with a testimony of Your faithfulness. Amen.
OLÓRUN YIO RÁNTÍ RE
IRUGBIN NAA
ỌLỌRUN si ranti Noa, ati ohun alaaye gbogbo, ati gbogbo ẹran-ọ̀ sin ti o wà pẹlu rẹ̀ ninu ọkọ̀ . Genesisi 8:1
Ni igba ti Olórun ba se ranti, ko tumo si pe o gbagbe. O tumo si pe O yan lati gbe igbese nitori tire ni akoko ti o ti yan. Noa duro sinu oko nigbati ikun omi gba aye. O ni lati je akoko ti o pé,̣ ti o si dáké ̣ róṛ ó ̣ sugbon Olórun ranti re. Be e gege ni Olorun maa ranti re ni akoko iduro dee. Yio ranti adura re, omije re, ododo re, ati ebo re. Nigbati Olorun ba ranti, ilekun a si, ileri a se, eri a waye. Di igbagbo re mu. Igba iranti re n bo wa.
BIBELI KIKA: Genesisi 8:1-12
ADURA: Baba, mo dupe pe O ranti mi. Je ki igba iduro mi dopin pelu eri ododo Re. Amin.