A MEASURE OF FAITH
THE SEED
“And Jesus said unto them, Because of your unbelief: for verily I say unto you, If ye have faith as a grain of mustard seed, ye shall say unto this mountain, Remove hence to yonder place; and it shall remove; and nothing shall be impossible unto you.” – Matthew 17:20 (KJV)
Every believer has a measure of faith. We exercise faith daily without realizing it—trusting a chair to hold us, a vehicle to move, or an unseen radio wave to work. How much more should we trust the Almighty God who never fails? Even faith as small as a mustard seed can move mountains when placed in God. Faith is not about size but about trust in God’s ability. Choose today to trust Him completely, regardless of what you see or feel.
BIBLE READINGS: Hebrews 11:1–12 (KJV)
PRAYER: Lord, help my unbelief. Strengthen my faith to trust You completely in all things, in Jesus’ name. Amen.
OSUWON IGBAGBO
IRUGBIN NAA
Jesu si wi fun wọn pe, Nitori aigbagbọ́ nyin ni: lõtọ ni mo sá wi fun nyin, Bi ẹnyin ba ni igbagbọ́ bi wóro irúgbin mustardi, ẹnyin o wi fun òke yi pe, Ṣi nihin lọ si ọ̀hun, yio si ṣi; kò si si nkan ti ẹ ki yio le ṣe. Matteu 17:20
Gbogbo onigbagbo loni osuwon igbagbo. A nse ise igbagbo lojoojumo laimo, bii ki a fi okan tan aga ijoko lati di wa mu, oko ki o gbera, tabi ero igbounsafefe lati sise. Melo melo waa ni lati fi okan tan Olorun alagbara ti kii kuna. Igbagbo ti o kere bi horo mustadi, o le si oke ni idi, ti a ba fi sinu Olorun. Igbagbo kiise nipa iwon sugbon nipa ki a fi okan tan agbara Olorun. Yan loni lati gbekele patapata, lainifise oun ti o ri tabi oun tio lero
BIBELI KIKA: Heberu 11:1-12
ADURA: Oluwa, ran aigbagbo mi lowo, fi okun fun igbagbo mi lati gbekele o patapata ninu oun gbogbo ni oruko Jesu. Amin.