FIGHTING THE GOOD FIGHT OF FAITH
THE SEED
“Fight the good fight of faith, lay hold on eternal life, whereunto thou art also called, and hast professed a good profession before many witnesses.” – 1 Timothy 6:12 (KJV)
The Christian life is not passive; it’s a daily battle to uphold righteousness and faith. Paul reminded Timothy to hold firmly to eternal life and fight for the faith he professed. Distractions and evil surround us, but we are called to stand firm. This fight isn’t fought with physical weapons but with spiritual endurance, prayer, obedience, and trust in Christ. Stand your ground and guard your salvation fiercely—it is your crown of glory.
BIBLE READINGS: Ephesians 6:10–18 (KJV)
PRAYER: Lord, help me to fight the good fight of faith. Strengthen me to stand firm in Your grace and to finish my race well. Amen.
JIJA IJA RERE TI IGBAGBO
IRUGBIN NAA
Mã jà ìja rere ti igbagbọ́, di ìye ainipẹkun mu ninu eyiti a gbé pè ọ si, ti iwọ si ṣe ijẹwo rere niwaju ẹlẹri pupọ̀. 1 Timoteu 6:12
Igbe aye ti kristeni kiise ti idake roro, o je oju ogun ojoojumo lati gbe ododo ati igbagbo ro. Paulu ran Timoteu leti lati di iye ayeraye mu sinsin ki o si ja fun igbagbo ti o gba. Idaamu ati ibi lo yi wa ka sugbon a pe wa lati duro sinsin. Ija yi kiise eyi ti a fi oun ija ti aye ja sugbon pelu ifarada tie mi, adura, igboran ati igbekele ninu Kristi. Duro lori ese re ki o si pa igbagbo re mo takuntakun- oun ni ade ogo re.
BIBELI KIKA: Efesu 6:10-18
ADURA: Oluwa ranmilowo lati ja ija rere ti igbagbo. Fun mi ni agbara lati duro sinsin ninu ore ofe re kin si pari ere ije mi daradara. Amin.