STAY CONNECTED TO THE SOURCE

THE SEED

“For in him we live, and move, and have our being; as certain also of your own poets have said, For we are also his offspring.” – Acts 17:28 (KJV)

Many believers treat God like a PRN medication—only turning to Him in emergencies. But God is our Source, the One who sustains every aspect of our lives. Just as a river dries up when it disconnects from its source, we lose spiritual vitality when we drift from God.

Maintaining a constant relationship through worship, prayer, and trust keeps us strong and fruitful. Jesus Himself relied on His Father for everything. Daily connection to the Source keeps our spiritual life fresh and our faith unshakable.

BIBLE READINGS:  John 15:1–8 (KJV)

PRAYER: God, help me to stay connected to You always. Revive and strengthen me to live in constant dependence on You, in Jesus’ name. Amen.

NI ASOPO PELU ORISUN

IRUGBIN NAA

Nitori ninu rẹ̀ li awa gbé wà li ãye, ti awa nrìn kiri, ti a si li ẹmí wa; bi awọn kan ninu awọn olorin, ẹnyin tikaranyin ti wipe, Awa pẹlu si jẹ ọmọ rẹ̀. Ise Aposteli 17:28

Opolopo onigbagbo nse Olorun bii oogun ti won nlo ni pajawiri, sugbon Olorun ni orisun wa, eni to di gbogbo igbesi aye wa mu. Gege bi odo ti n gbe nigba ti o ba gbagbe orisun, a nso agbara emi nu nigba ti a ba jina si Olorun. Ibasepo nigbagbogbo nipa ijosin, adura ati igbekele, oun ni o nfun wa ni agbara, ti a sin so eso. Jesu tikara re, o gbe ara le baba re fun oun gbogbo. Isopo lojoojumo si orisun , o nmu igbe aye emi wa di otun. O sin mu igbagbo wa rin le.

BIBELI KIKA: Johannu 15: 1-8

ADURA: Olorun, ranmilowo lati wa ni isopo pelu re ni gbogbo igba. Tamiji , ki o si fun mi ni okun lati maa gbe ara le o ni oruko Jesu. Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *