BUILD GODLY CHARACTER

THE SEED

“Neither do men light a candle, and put it under a bushel, but on a candlestick; and it giveth light unto all that are in the house. Let your light so shine before men, that they may see your good works, and glorify your Father which is in heaven.” – Matthew 5:15–16 (KJV)

Character matters deeply to God. A godly character reflects His light in a dark world. It shapes how others perceive us and influences those around us. Good character attracts people to Christ, while a poor character pushes them away. Building godly character requires discipline, daily intake of the Word, and yielding to the Holy Spirit. Your true nature is revealed not by what you say, but by how you live. Let your life shine so brightly that others glorify God because of you.

BIBLE READINGS:  Philippians 2:12–16 (KJV)

PRAYER: Father, give me the grace and discipline to build a godly character. Let my life reflect Your wisdom, light, and excellence, in Jesus’ name. Amen.

KO IWA BI OLORUN

IRUGBIN NAA

Bẹ̃ni a kì itàn fitila tan, ki a si fi i sabẹ òṣuwọn; bikoṣe lori ọpá fitila, a si fi imọlẹ fun gbogbo ẹniti mbẹ ninu ile.   Ẹ jẹ ki imọlẹ nyin ki o mọlẹ tobẹ̃ niwaju enia, ki nwọn ki o le mã ri iṣẹ rere nyin, ki nwọn ki o le ma yìn Baba nyin ti mbẹ li ọr

Iwa je Olorun logun lopolopo. Iwa bi Olorun ma nfi imole re han ninu aye okunkun. O ma nfi iru eni ti a je han si awon to yi wa ka. Iwa to dara ma nfa awon eniyan wa si odo Kristi, sugbon iwa buburu ma nle won lo. Kiko iwa bi Olorun nilo ikora eni ni ijanu, kika oro Olorun lojoojumo, ati fifi ara eni sile fun Emi Mimo. Igbe aye ti ongbe lo ma fi bio ti ri gangan han, kiise oun ti o ban so. Jeki igbe aye re maa tan imole , ki awon eniyan le maa yin Olorun nitori tiyin.

BIBELI KIKA: Fillipi 2:12-16

ADURA: Baba, fun mi ni oore ofe ati agbara lati ko iwa bi Olorun. Je ki aye mi se afihan ogbon re, imole ati iserere ni oruko Jesu. Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *