GUARDING THE MIND
THE SEED
“Set your affection on things above, not on things on the earth.” – Colossians 3:2 (KJV)
The human mind is a powerful battlefield. Whoever controls the mind, controls the outcome. The enemy knows this, which is why he tirelessly targets the believer’s thoughts to gain control. If he succeeds in taking over your mind, he influences your decisions and actions.
Proverbs 4:23 warns us to guard our hearts diligently. A mind focused on Christ will discern the enemy’s lies and resist his traps. Being spiritually mindful means setting your thoughts on God’s truth and living each day with eternity in view.
BIBLE READINGS: Philippians 4:6–9 (KJV)
PRAYER: Lord Jesus, keep my mind fixed on You. Help me to resist the enemy’s deceit and walk in victory daily, in Jesus’ name. Amen.
ṢIṢO OKAN RE
IRUGBIN NAA
Ẹ mã ronu awọn nkan ti mbẹ loke kì iṣe awọn nkan ti mbẹ li aiye. Kolosse 3:2
Oju ogun to lagbara ni okan eniyan je,eni ti o ba nse akoso okan , oun ni o nse akoso atubotan. Ota mo eleyi, nitorinaa ni o se ntiraka lati gba isakoso ero okan onigbagbo. Ti o ba yega lati gba akoso okan re, yio maa dari isesi ati ihuwasi re. Owe 4:23 se ikilo fun wa lati so okan wa . okan ti o fojusi Kristi yio mo awon iro ota, yio si sa fun panpe re. ti eniyan ba ni ero ti emi, o tunmo si wipe o fi ero re sori otito Olorun, o si ngbe igbe aye ojoojumo pelu ayerare lokan re.
BIBELI KIKA: Fillipi 4:6-9.
ADURA: Jesu Oluwa, Jeki okan mi kio wa lara re. ranmilowo lati koju ija si itanje ota , ki nsi rin ninu isegun lojoojumo ni oruko Jesu Amin.