THE SEED
“He hath made every thing beautiful in his time.” – Ecclesiastes 3:11a (KJV)
Evelyn desired a car when her friends were buying theirs, but the wrong path to get it was laced with compromise. She waited, and in God’s time, she received far more than she had imagined — with no strings attached. God is never late. His timing may not always align with our desires, but it is always perfect. When we wait on Him, what we receive comes with peace, not pressure. Don’t rush ahead of God; His appointed time is always worth the wait.
BIBLE READINGS: Psalm 37:3–9 (KJV)
PRAYER: Lord, fill me with patience to wait for Your appointed time and to trust Your perfect plan for my life. Amen.
ASIKO OLORUN LO DARA JU
IRUGBIN NAA
O ti ṣe ohun gbogbo daradara ni ìgba tirẹ̀; pẹlupẹlu o fi aiyeraiye si wọn li aiya, bẹ̃li ẹnikan kò le ridi iṣẹ na ti Ọlọrun nṣe lati ipilẹṣẹ titi de opin. Oniwaasu 3:11
Evelin nfe lati ra oko nigba ti awon ore re naa na tiwon, sugbo ona lati ri, o je ona ti ko to. O duro, ni igba ti o to asiko Olorun, oun ti o ri gba, o koja oye re, laisi ounkon ti o so mo. Olorun o kii pe de, asiko re le ma jo mo ife wa, sugbon o ma nje pipe. Nigba ti a ba duro de, oun ti a ma rigba ma wa pelu Alafia kiise pelu ipa. Mase sare koja Olorun. Akoko ti o ba yan ma ndara.
BIBELI KIKA: Orin Dafidi 37:3-9
ADURA: Oluwa, kun mi fun suuru lati duro de asiko ti o yan, ati lati gbekele eto pipe re fun aye mi. Amin.