THE SEED
“The steps of a good man are ordered by the Lord: and he delighteth in his way. Though he fall, he shall not be utterly cast down: for the Lord upholdeth him with his hand.” – Psalm 37:23–24 (KJV)
We make plans daily, but without God’s guidance, even the best intentions can falter. When we delight in Him, He directs our steps. Though we may stumble, He lifts us up. God is a faithful guide and a strong support. Trusting His leading ensures that no fall will be permanent. As we walk with Him, He steadies our steps and upholds us with His unfailing hand.
BIBLE READINGS: Proverbs 3:5–10 (KJV)
PRAYER: Father, give me a heart that delights in You. Guide my steps and uphold me when I stumble. In Jesus’ name. Amen.
ITOSONA NIPASE OLORUN
IRUGBIN NAA
A ṣe ìlana ẹsẹ enia lati ọwọ Oluwa wá: o si ṣe inu didùn si ọ̀na rẹ̀. Bi o tilẹ ṣubu, a kì yio ta a nù kuro patapata; nitoriti Oluwa di ọwọ rẹ̀ mu. Orin Dafidi37:23-24
Ojoojumo ni a nse eto, sugbon laisi itosona, ero tio dara julo le kuna. Ti a ba nyo ninu re, yio ma dari igbese wa. Bi a ti kose, yio gbe wa soke. Olorun je olutona ododo ati alatilehin to lagbara. Igbekele ninu idari re je ko daju wipe ko si isubu ti yio wa lailai. Bi a se nbaa rin, o nto igbese wa, o si diwa mu pelu owo re ti kii kuna.
BIBELI KIKA: Owe 3:5-10
ADURA: Baba, fun mi ni okan to ni inudidun ninu re. To igbese mi ki o si dimi mu nigba ti mo ba kose ni oruko Jesu Amin.