THE SEED
“But he knoweth the way that I take: when he hath tried me I shall come forth as gold.” – Job 23:10 (KJV)
Job’s life shows that trials often precede testimonies. Even when falsely accused or mistreated, his faith remained steadfast. Similarly, believers must understand that difficulties, rejections, and challenges are part of God’s refining process. Endurance and patience build character and prepare us for greater glory. Every trial is a test to strengthen faith and refine our lives. Like gold tested in fire, we come forth purified and ready for God’s rewards. The challenges of today are the foundations of tomorrow’s testimony.
BIBLE READINGS: Job 23:1–12 (KJV)
PRAYER: Lord, grant me patience and steadfastness in times of trials, that I may come forth refined and victorious, in Jesus’ name. Amen.
IDANWO SAJU ERI
IRUGBIN NAA
Ṣugbọn on mọ̀ ọ̀na ti emi ntọ̀, nigbati o ba dan mi wò, emi o jade bi wura. JOBU 23:10
Igbe aye Jobu fihan wipe idanwo a maa siwaju eri. Nigbati won tile fi esun eke kan an, ti won ko si wu iwa daradara si, sibe igbagbo re dure sinsin. Bakan naa, onigbagbo gbodo ni oye wipe isoro, ikosile, ati ipenija wa lara awon ona ti Olorun ngba se wa ni asepe. Iforiti ati suru maa koni ni iwa rere, yoo si mu wa setan fun ogo ti o ga. Olukuluku idanwo ni nmu igbagbo le si, ti o si n tu aye wa se. Gege bi wura ti a n fi ina danwo, a o jade gege bi ẹniti a ti wemo, ti o si ti setan fun ere lati owo Olorun. Ipenija ti oni, awon ni ipinle eri ojo ola.
BIBELI KIKA: Jobu 23:1-12
ADURA: Oluwa, fun mi ni suru ati iduro sinsin ni akoko iponju, ki emi ki o le farahan gege bi ẹniti a ti tunse, ti o si ti segun ni oruko Jesu. Amin