THE SEED
“And he said, The things which are impossible with men are possible with God.” – Luke 18:27
With God, nothing is impossible. Just as He parted the Red Sea for the Israelites, brought fire down for Elijah, protected Daniel in the lions’ den, and kept the Hebrew boys safe in the fiery furnace, He can make the impossible possible in your life. Faith and trust in God open the door to miraculous outcomes. When we rely on Him fully, surrender our fears, and obey His Word, He turns tests into testimonies and shame into fame. God’s power is unlimited, and His promises are sure for those who place their confidence in Him.
BIBLE READINGS: Jeremiah 32:17–25 (KJV)
PRAYER: God of possibilities, intervene in the affairs of my life today and make the impossible possible, in Jesus’ name. Amen.
OLORUN MAA NSE OHUN TO DA BI ENIPE KO SEESE SE
IRUGBIN NAA
O si wipe, Ohun ti o ṣoro lọdọ enia, kò ṣoro lọdọ Ọlọrun. Luku 18:27
Ninu Oluwa, ohun gbogbo ni sise. Gege bi O ti pin okun niya fun awon omo Israeli, O ran ina sokale fun Elijah, O pa Danieli mo ninu iho kiniun, O yo Heberu meta ninu ina ileru, O le se awon ohun ti a ro pe ko seese ninu aye wa. Igbagbo ati igbekele ninu Olorun maa nsi ilekun fun iyanu. Nigbati a ba simi le Olorun patapata, ti a jowo eru wa, ti a si gboran si Oro Re, Yio so idanwo di eri, itiju di okiki fun wa. Agbara Olorun ko ni ipekun, ati awon ileri Re daju fun awon ti o gbekele won le E.
BIBELI KIKA: Jeremiah 32:17-25
ADURA: Olorun aseese, dasi oro aye mi loni, ki o si mu awon ohun ti ko seese, di sise, ni Oruko Jesu. Amin