LET GOD ARISE
THE SEED
“Let God arise, let his enemies be scattered; let those also who hate Him flee before Him.” Psalm 68:1
“Let” is a choice. When you invite God to arise in your life through worship, surrender, and bold faith He establishes His victory in places of resistance. He scatters what opposes His purpose and exchanges ashes for beauty, heaviness for praise. God’s arising doesn’t sidestep your participation: stand, sing, pray, obey. As you exalt Him, crooked places straighten and valleys lift (Isa. 40:4–5). His presence changes the atmosphere, and His peace steadies your steps. From famine to fullness, from mourning to dancing He is able. Believe, and make room for His rising. Praise is often the doorway through which God’s victory enters your battles.
BIBLE READINGS: Psalm 68:1–6
PRAYER: O God, arise in my life. Scatter every opposition and favour me by Your power. Amen.
JẸ́ KÍ OLORUN DÌDE
IRUGBIN NAA
Kí Ọlọ́run kí ó dìde, kí àwọn ọ̀tá rẹ̀ kí ó fọ́nká; kí àwọn ọ̀tá rẹ̀ kí ó sá níwájú rẹ̀. – Orin Dafidi 68:1
Nigba ti o ba pe Olorun lati dide ninu aye re – nipa isin, jijowo ohun gbogbo fun, ati pelu igbagbo – oun yóò fi idi isegun Re mule ani ninu idojuko re. Oluwa a máa fọ́́ oun gbogbo to ba lodi si ipinnu Re, ádé ẹwà dípò eérú, àti aṣọ ìyìn dípò ìpòrúru ọkàn. Wipe Olorun dide ko ni wipe iwo ko ni ipa lati ko: o ni lati duro, korin, gbadura ki o si se igboran. Bi iwo si ṣe ń yìín, gbogbo ona wíwọ́ ni a ó sọ di títọ́ àti gbogbo àfonífojì ni a ó gbé sókè. Ìyàn ni a so yipada si ọ̀pọ̀, ikaanu ni a o yipada si ijo – Oluwa ní agbara lati see. Gbagbo, ki o si fi àyè sile fun idide Re. Iyin máa n se ona abawole ti isegun Olorun n gba wole si idojuko re.
BIBELI KIKA: Orin Dafidi 68:1-6
ADURA: Olorun o, dide si aye mi. Fón gbogbo ota Re ká ki O si se oju rere Re si mi nipa agbara Re. Amin.