STUDY THE WORD

STUDY THE WORD

THE SEED

“Study to shew thyself approved unto God… rightly dividing the word of truth.”  2 Timothy 2:15

Scripture saves, sanctifies, and equips. To attempt Christian living without the Word is like leaping from a plane without a parachute. God forms workers who need not be ashamed by training their minds and hearts in His truth. Jesus answered every wilderness temptation with “It is written.” So must we. Open the Bible not as a box to tick but as a voice to hear, a treasure to mine, and a sword to wield. Meditation turns text into strength and instruction into transformation. Make time, make a plan, and make it prayerful. Approval before God outweighs applause before people. The Word you store today becomes the wisdom and weapon you need tomorrow.

 

BIBLE READINGS:  Hebrews 4:12

PRAYER: Lord, give me grace to delight in, meditate on, and rightly handle Your Word. Amen.

 

ṢE ÌṢÀRÒ NÍNÚ Ọ̀RỌ̀ OLORUN

IRUGBIN NAA

Ṣaápọn láti fi ara rẹ̀ hàn níwájú Ọlọ́run bi ẹni tí ó yege àti òṣìṣẹ́ tí kò ní láti tijú, tí ó ń pín ọ̀rọ̀ òtítọ́ bí ó ti yẹ. – 1 Timotiu 2:15

Iwe Mimo a máa gba ni, soni di mimo, a si ma mu wa mura sile. Eniyan to fe di Kristeni lai ni oro Olorun dabi eni ti o fe fo sile lati inu oko ofurufu lai ni oun abo. Olorun máa n se awon olusise ti kii n tiju nipa kíkọ́ okan won ninu otito Re. Idahun Jesu si gbogbo idanwo satani ninu aginju ni wipe “A ti kọọ́”. Awa naa ni lati se bakanna. Ṣí Bibeli re, kii se lati ka lasan  bikose lati gbọ́ ohun  re – oun isura lati rí mú, ati ida lati mu dani. Isaro máa n so iwe di agbara, a si so itonisona di iyipada rere. Fi akoko sile, se eto, pelu adura. Ojurere niwaju Olorun ju iyin niwaju eniyan. Oro ti o ba fi pamo loni yóò je ogbon ati oun ija ti iwo yoo nilo ni ojo ola.

BIBELI KIKA: Heberu 4: 12

ADURA: Oluwa, fun mi ni oore-ọfẹ lati ni inu-didun, ṣe àṣàrò lori, ati ki o mu Ọrọ Rẹ tọ́. Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *