TOTAL SUBMISSION

TOTAL SUBMISSION

THE SEED

“Jesus said unto him, ‘Thou shalt love the Lord thy God with all thy heart, and with all thy soul, and with all thy mind.’” Matthew 22:37

Submission is more than surrendering a moment; it is gladly placing God first in every sphere affections, ambitions, and decisions. Inner conflict thrives where self-will competes with God’s will. Peace comes when love leads to obedience. We cannot live in two worlds pleasing the flesh and pleasing the Lord. When God closes a door, don’t crawl through a window of compromise. Yield to the Spirit’s cleansing and healing work; He reorders desires and realigns steps. To submit is not to lose yourself; it is to find your true life in Christ.

Love proves itself by obedience, and obedience opens the way to abiding joy.

BIBLE READINGS:  James 4:7–10

PRAYER: Father, teach me whole-hearted submission. I choose Your will above mine today and always. Amen.

 

FÍFI OHUN GBOGBO SÍLẸ̀

IRUGBIN NAA

Jesu dáhùn pé, “‘Fẹ́ Olúwa Ọlọ́run rẹ pẹ̀lú gbogbo ọkàn rẹ, gbogbo ẹ̀mí rẹ àti gbogbo inú rẹ.’ – Matiu 22:37

 

Fifi ara eni sile ju jijowo akoko kan lo. O je fifi Olorun se àkọ́kọ́ ninu oun gbogbo – ife wa, afojusun ati ipinnu wa. Okan yóò kun fun rogbodiyan nigba ti ife-ara-eni ba n ba ife Olorun ja. Alaafia máa n wá nigba ti ife ba yori si igboran. A ko le gbe igbe aye meji – ki eniyan máa te ara lorun ko tun ma te Olorun lorun. Ti Olorun ba ti ilekun kan, mase pon ferese wole lati lodi sii. Jowo ara re fun iṣẹ́ iwenimo ati iwosan ti Emi; Òun nikan lo le tu ona re tò. Fifi ara re sile kii  se wipe o so ara re nu; o ja si wipe o wá emi re ri ninu Kristi. Ife a máa fi ara han nipa igboran, igboran a si je ona si ayo.

BIBELI KIKA: Jakobu 4: 7-10

ADURA: Baba, ko mi lati jowo oun gbogbo fun o. Mo yan ife Re ju ife ara mi lo loni ati titi lai. Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *