UNBELIEF WEAKENS THE POWER WITHIN
THE SEED
“And Jesus said unto them, Because of your unbelief: for verily I say unto you, If ye have faith as a grain of mustard seed… nothing shall be impossible unto you.” — Matthew 17:20 (KJV)
Unbelief robbed the disciples of demonstrating God’s power. They prayed, but without faith, and nothing happened. Many believers today also pray but doubt within, and wonder why results do not follow. Doubt limits the flow of God’s power.
w miracles in His hometown because of their unbelief. Faith is the channel through which the power of God moves. Without it, even fervent prayer can be empty noise. Believing God is not always easy, but it is essential to living in victory. When you pray, believe that He hears and will act. Even faith as small as a mustard seed can move mountains.
Reflection: Faith unlocks what doubt holds back.
BIBLE READING: Matthew 17:15–20
PRAYER: Father, increase my faith. Help me to trust You fully and never limit Your power through unbelief. Amen.
AIGBAGBO MAA NMU AARE BA AGBARA TI MBE NINU WA
IRUGBIN NAA:
Jesu si wi fun wọn pe, Nitori aigbagbọ́ nyin ni: lõtọ ni mo sá wi fun nyin, Bi ẹnyin ba ni igbagbọ́ bi wóro irúgbin mustardi, ẹnyin o wi fun òke yi pe, Ṣi nihin lọ si ọ̀hun, yio si ṣi; kò si si nkan ti ẹ ki yio le ṣe. Matteu 17:20
Aigbagbo ni ko je ki awon omo ehin ri agbara Olorun lo. Nwon gba adura laisi igbagbo, ko si si ohunkohun to sele. Opo onigbagbo lode oni bakanna ni nwon ngbadura sugbon ti won nse iyemeji ninu won, won si nwoye idi ti won ko fi nri esi adura won. Iyemeji maa ndin owo agbara Olorun ku. Jesu ko se ise iyanu pupo ni ilu abinibi Re nitori aigbagbo won. Igbagbo ni ona ti agbara Olorun nrin. Laisi eyi, adura ti a fi itara gba le je ariwo lasan. Gbigba Olorun gbo kii rorun ni opo igba sugbon o je dandan, ki a baa le maa gbe ninu isegun. Nigbati o ba gba adura, gbagbo wipe O gbo ati wipe yio se. Bi igbagbo re ba tile kere bi irungbin mustadi, o le si oke ni idi.
EKO: Igbagbo maa nse awari ohun ti iyemeji ju danu
BIBELI KIKA Matteu 17:15-20
ADURA: Baba, busi igbagbo mi. Ranmi lowo lati gbekele O patapata, ki nmase fi aigbagbo di agbara Re lowo. Amin