BUILDING A RELATIONSHIP WITH GOD

BUILDING A RELATIONSHIP WITH GOD

THE SEED

“And ye shall seek me, and find me, when ye shall search for me with all your heart.” — Jeremiah 29:13 (KJV)

God doesn’t just want distant followers; He desires deep relationship. A close walk with Him brings guidance, comfort, strength, and transformation. It is not measured by religious activities alone, but by a heart that longs to know and love Him. This kind of intimacy requires consistency and intentional pursuit. Spending time in prayer, studying the Word, listening to His voice, and walking in obedience helps build trust. The more you seek Him, the more you recognise His voice and align with His will. A thriving relationship with God becomes the anchor of your life, even when everything else shakes.

Reflection: A heart that seeks God never remains the same.

BIBLE READING: Psalm 145:18–20

PRAYER: Lord, draw me close to You. Help me seek You with my whole heart and grow in intimate fellowship with You. Amen.

 

NINI IBASEPO PELU OLORUN

IRUGBIN NAA:

Ẹnyin o si ṣafẹri mi, ẹ o si ri mi, nitori ẹ o fi gbogbo ọkàn nyin wá mi. Jeremiah 29:13

Olorun ko fe awon ti nsin sugbon ti won jina si I; O fe ibasepo to denu. Biba Olorun rin maa nmu itoni, itunu, okun, ati ayipada wa. Kii se nipa ise isin nikan, sugbon nipa okan to n pongbe lati mo On ati lati feran Re. Iru ajosepo yii nilo ki a maa se deede ati ki a si ni ilepa atokanwa. Lilo akoko wa ninu adura, sise asaro ninu Oro Olorun, fifi eti sile si Ohun Re ati ririn ninu igboran maa nse iranwo lati ni igbekele. Bi o ba se nwa A si, bee naa ni iwo yoo da Ohun Re mo ti iwo yio si wa ni ibamu pelu ife Re. Ibasepo to danmoran pelu Olorun yio di idakoro aye re, paapaa nigbati ohun gbogbo ba nye.

ERO: Okan ti nwa Olorun, kii wa bakan naa.

BIBELI KIKA: Orin Dafidi 145:18-20

ADURA: Oluwa, fami mora sodo Re. Ranmilowo lati wa O pelu gbogbo okan mi, ki nsi dagba ninu idapo pelu Re. Amin

 

 

 

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *