LEADERSHIP THAT SERVES

LEADERSHIP THAT SERVES

THE SEED

“Ye know that the princes of the Gentiles exercise dominion over them… But it shall not be so among you: but whosoever will be great among you, let him be your minister.” — Matthew 20:25–26 (KJV)

In God’s kingdom, greatness is measured in towels, not titles. Authority is stewardship, not superiority. Leaders are called to serve, protect, and build up the flock, remembering they will give account to the Chief Shepherd.

Pride and power games ruin ministries and scatter sheep. Saul’s story warns us: seeking human approval over divine obedience forfeits destiny. But Christ, our model, stooped to wash feet and to lay down His life—this is leadership in the shape of the cross. Let every leader be an example in word, conduct, love, faith, and purity. Influence anchored in humility will always outlast authority claimed by force.

Reflection: True authority grows as freely as you serve.

BIBLE READING: Matthew 20:25–28

PRAYER: Father, clothe every leader with humility and wisdom. Make our leadership Christ-shaped—serving, steady, and surrendered to Your will. Amen.

 

ADARI TI NSIN NI

IRUGBIN NAA:

Ṣugbọn Jesu pè wọn sọdọ rẹ̀, o si wipe, Ẹnyin mọ̀ pe awọn ọba Keferi a ma lò agbara lori wọn, ati awọn ẹni-nla ninu wọn a ma fi ọlá tẹri wọn ba. Ṣugbọn kì yio ri bẹ̃ lãrin nyin: ṣugbọn ẹnikẹni ti o ba fẹ pọ̀ ninu nyin, ẹ jẹ ki o ṣe iranṣẹ nyin. Matteu 20:25-26

Ni ijoba orun, a ko fi oruko tabi ipo se osuwon ola ati agbara. Ipo ase je ipo iriju, ki se ipo enito ga julo. Awon olori gbodo je iranse, won gbodo dabo bo, ki won si mu agbo dagba si, ki won si maa ranti wipe won o jiyin fun Olori Oluso agutan. Igberaga ati agbara ma nba ise iranse je, a si mu awon agutan da ra. Itan oba Saulu se ikilo fun wa, wiwa atileyin awon eniyan ju igboran si ase Olorun nmuni padanu ayanmo. Sugbon Kristi, eniti nse awokose wa, bere lati we ese awon omo eyin Re, O si tun fi emi Re lele. Eyi ni idari ti o tona nipa agbelebu. E je ki gbogbo adari je apere rere ninu oro, ise, ife, igbagbo, ati iwa mimo. Itoni pelu irele, o bori ase ti a nfi ipa muni tele.

ERO: Ase tooto ma ndagba nigbati a ba sin lai roju.

BIBELI KIKA: Matteu 20:25-28

ADURA: Baba, wo gbogbo awon adari ni ewu irele ati ogbon. Je ki idari won dabi ti Kristi, ki won ma sin ni, ki won si jowo ohun gbogbo fun ase yin. Amin

 

 

 

 

 

 

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *