TRUSTING GOD’S SECRET THINGS

TRUSTING GOD’S SECRET THINGS

THE SEED

“I have yet many things to say unto you, but ye cannot bear them now… Howbeit when he, the Spirit of truth, is come, he will guide you into all truth.” — John 16:12–13 (KJV)

God does not reveal everything at once. Out of love and wisdom, He gives light we can carry and holds back what would distract or overwhelm. Our part is trust—walking in the light we have while we wait for the light we need. Some answers are timed, some mysteries are holy, and some directions unfold step by step. The Spirit guides, not by satisfying curiosity, but by leading us into truth that forms Christ in us. Faith rests in God’s character when His explanations are withheld. Do not confuse silence with absence. Keep obeying the last clear instruction, and in due season, fresh guidance will come.

Reflection: Faith thrives when you trust the Guide more than the map.

BIBLE READING: John 16:12–15

PRAYER: Lord, teach me to trust Your timing. Help me walk faithfully in today’s light and wait humbly for tomorrow’s guidance. Amen.

 

GBIGBEKELE OHUN IKOKO TI OLORUN

IRUGBIN NAA:

Mo ni ohun pipọ lati sọ fun nyin pẹlu, ṣugbọn ẹ kò le gbà wọn nisisiyi. Ṣugbọn nigbati on, ani Ẹmí otitọ ni ba de, yio to nyin si ọ̀na otitọ gbogbo; nitori kì yio sọ̀ ti ara rẹ̀; ṣugbọn ohunkohun ti o ba gbo, on ni yio ma sọ: yio si sọ ohun ti mbọ̀ fun nyin. Johannu 16:12-13

Olorun ki fi ohun gbogbo han lekan naa. Sugbon nitori ife ati ogbon Re, o tan imole si eyi ti a le mo, sugbon o pa eyi ti ogbon wa ko le gbe mo fun wa. Tiwa ni ki a gbekele E – ki a ma rin ninu imole ti a ni nigba ti a nreti imole ti a nilo. Awon idahun kan ni akoko, awon aditu miran je mimo, awon ona miran ma nyeni nipele nipele. Emi ntoni, kii se nipa wiwadi ohun, sugbon O ntowa sinu otito ti nse Kristi ninu wa. Igbagbo a maa simi le eniti Olorun je nigbati Olorun ko ba tile soro. Mase ro wipe Olorun ko si lodo re nitoripe o ko gbo ohun Re. Ma gboran si ase Re, nigba ati akoko, idari otun yio de.

ERO: Igbagbo maa ndagba nigbati o ba gbekele itoni ju ajuwe ona lo.

BIBELI KIKA: Johannu 16:12-15

ADURA: Oluwa, ko mi lati gbekele akoko Re. Ranmilowo lati fi otito rin ninu imole ti oni, ki nsi fi irele duro de itoni ti ola. Amin

 

 

 

 

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *