HEALING IN THE WORD

HEALING IN THE WORD

THE SEED

“For they are life unto those that find them, and health to all their flesh.” — Proverbs 4:22 (KJV)

The Word of God is not just letters it is life and health to all who believe. Just as medicine works in the body, the Word works in the spirit and soul, bringing healing and wholeness. It is the believer’s access to divine health, which no earthly remedy can match. To receive this divine flow, we must pay attention to the Word, meditate upon it, and store it in our hearts. When the Word takes root, it releases life, strength, and healing from within. Christ, the living Word, dwells in us to sustain and quicken our bodies. In a sick and broken world, believers can walk in supernatural health by staying connected to the River of Life Jesus Himself. Make His Word your daily medicine and source of strength.

Reflection: God’s Word is a healing river that never runs dry.

 

BIBLE READING: Proverbs 4:20–23

PRAYER: Lord Jesus, let Your Word flow through my life and keep me in divine health daily. Amen.

 

IMULARADA NINU ORO NAA

IRUGBIN NAA:

“Nítorí ìyè ni wọ́n jẹ́ fún gbogbo ẹni tí ó rí wọn àti ìlera fún gbogbo ara ènìyàn.” Owe 4:22

Oro Olorun ki i se iwe lasan, o je iye ati ilera fun gbogbo awon ti o gbagbo. Gege bi oògùn tii sise ninu ara, Oro Olorun naa n sise ninu emi ati okan, o si n mu imularada pipe wa. O je ona ti onigbagbo fi ngba ilera atokewa, eyi ti aye ko lee fun ni. Lati gba imularada yii, a gbodo fiyè si oro naa, ki a se asaro lori re, ki a si fi pamo sinu okan wa. Nigba ti Oro naa ba gbinle, yoo mu iye, agbara ati imularada jade wa. Kristi, eni ti n se Oro Iye na, n gbe ninu wa lati gbe wa ro ati lati sọ wa ji. Ninu aye ti o kun fun aisan ati iruju, onigbagbo le rin ninu ilera atorunwa, nipa diduro ni ibamu pelu orisun iye – àní Jesu. Je ki oro Re je oògùn ati orisun agbara re lojoojumo.

Oro Agbeyewo: Oro Olorun je odo imularada ti ki i gbe.

 

BIBLE READING: Owe 4:20-23

PRAYER: Jesu Oluwa, je ki oro Re san ka gbogbo aye mi, ki o si pa mi mo ninu ilera atokewa lojoojumo. Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *