RUNNING TO THE FINISH
THE SEED
“I have fought a good fight, I have finished my course, I have kept the faith.” — 2 Timothy 4:7 (KJV)
Apostle Paul could declare these words confidently because he gave his all to the assignment God entrusted to him. He did not run half the race or hold back in service. He lived his life with intentional faithfulness and relentless commitment to God’s purpose. Life is a race with a finish line, and every believer will one day stand before God’s evaluation. The true measure of a good fight is not perfection but faithfulness to the very end. We must give our best in our families, ministries, workplaces, and communities—not halfway effort, but wholehearted devotion.
Don’t allow the weight of past failures or present distractions to hold you back. Run with endurance, stay faithful, and keep the faith until the finish line.
Reflection: Faithfulness today prepares your crown tomorrow.
BIBLE READING: 2 Timothy 4:6–8
PRAYER: Lord, help me to finish strong and keep the faith in every season of my journey. Amen.
SISA ERE DE OPIN
IRUGBIN NAA:
“Èmi ti ja ìjà rere, èmi tí parí iré-ìje mi, èmi ti pa ìgbàgbọ́ mọ́;” II Timotiu 4:7
Paulu Aposteli le so oro yii pelu igboya nitori o fi gbogbo ohun ti o ni fun ise ti Olorun gbe le lowo. Ko sa ere naa de aarin tabi fa seyin ninu ise na. O gbe igbe aye otito ati ifaraji tokantokan fun ipinnu Olorun. Eré ìje ti o ni opin ni aye yii je, gbogbo onigbagbo ni yoo si duro niwaju Olorun fun ayewo. Isuwon otito fun ija rere ki i se nipa jije eni ti o pé, bikose wipe ki a je olotito titi de opin. A gbodo sa gbogbo ipa wa wa ninu idile, ise-iranse, ibi ise, ati ni agbegbe wa. Ki i se ise ààbọ̀ sugbon ifaraji tokan tokan. Mase je ki eru isubu atijo tabi isoro akoko yii fa o seyin. Sare pelu ifarada, je olotito sibe, ki o si pa igbagbo mo titi de opin.
Oro Agbeyewo: Isotito loni nse ipese ade re lola.
BIBLE READING: II Timotiu 4:6-8
PRAYER: Oluwa, ran mi lowo lati pari pelu agbara, ati lati pa igbagbo mo ni gbogbo akoko irin ajo mi. Amin.