AGREEING WITH GOD

AGREEING WITH GOD

THE SEED

“And they overcame him by the blood of the Lamb, and by the word of their testimony.” — Revelation 12:11 (KJV)

Agreement is a powerful force in the realm of the spirit. Even the promises of God require our active agreement to be fully manifest in our lives. The blood of Jesus is all-sufficient, but it works when we testify to what it has accomplished. Likewise, the enemy also seeks agreement—through fear, silence, or unbelief. Refusing to resist him is a form of silent agreement with his lies. When we declare God’s truth over every situation, we break agreement with darkness and enforce victory. Keep declaring what God says, not what circumstances dictate. Victory is won when your testimony aligns with Christ’s finished work.

Reflection: Heaven backs every believer who agrees with the finished work of Christ.

 

BIBLE READING: Revelation 12:10–12

PRAYER: Father, let my confession always agree with Your Word, and let my life testify of Your victory. Amen.

 

WIWA NI IBAMU PELU OLORUN

IRUGBIN NAA:

“Wọ́n sì ti ṣẹ́gun rẹ̀ nítorí ẹ̀jẹ̀ ọ̀dọ́-àgùntàn náà, àti nítorí ọ̀rọ̀ ẹ̀rí wọn.…” Ifihan 12:11

Adehun je nnkan alagbara ninu emi. Ileri Olorun paapaa nilo ibamu wa lati wa si imuse ninu aye wa. Eje Jesu to fun ohun gbogbo, sugbon o maa nsise nigba ti a ba jeri si ohun ti a ti owo Re se. Bakanna, ota na nwa ibamu nipa eru, idakeje, ati aigbagbo. Kiko lati dekun re je ona kan ti a fi gba lati wa ni ibamu pelu arekereke re. Nigba ti a ba kede otito Olorun lori gbogbo ipo, awa n ba adehun okunkun je, a si nse imuduro isegun. Tun bo maa kede ohun ti Olorun so botiwu ki ipo ti o wa ri. Nigbati eri re ba wa ni ibamu pelu ise asepe Kristi, iwo o ri isegun gba.

Asaro: Orun maa nse atileyin fun gbogbo onigbagbo ti o ba wa ni ibamu pelu ise asepe Kristi.

 

BIBELI KIKA: Ifihan 12:10-12

ADURA: Baba, je ki ijewo mi maa wa ni ibamu pelu oro Re, si je ki aye mi jeri isegun Re. Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *