APPOINTED TIMES

APPOINTED TIMES

THE SEED

“There is a time for everything, and a season for every activity under the heavens.” — Ecclesiastes 3:1 (NIV)

Everything has divine timings and seasons. Time is not ours to control; it is entrusted to us by God. How we use it determines the fruit we bear in each season. Seasons of sowing will not last forever, nor will seasons of reaping. Each one requires wisdom, diligence, and faithfulness. A life lived without time consciousness wastes divine opportunities.

Learn to recognise God’s timing and align your actions with His will. When we walk in step with His timing, everything falls into place.

Reflection: God’s timing shapes life’s seasons—use your time well.

 

BIBLE READING: Ecclesiastes 3:1–8

PRAYER: Lord, teach me to value time and use it for Your glory. Amen.

 

AWON AKOKO TI A TI YAN

IRUGBIN NAA:

“Olukulùku ohun li akoko wà fun, ati ìgba fun iṣẹ gbogbo labẹ ọrun.” – Oniwaasu 3:1

Ohun gbogbo ni o ni akoko ati igba ti a ti yan lati oke wa. Akoko ki i se tiwa lati dari; a fi le wa lowo lati odo Olorun ni. Bi a ba se loo ni yo so iru eso ti a o so ni akoko naa. Akoko eso gbingbin ki i se lailai, bee na ni akoko ikore. Gbogbo re nilo ogbon, aise imele, ati isododo. Aye ti a ba gbe lai mo iyi akoko yoo so ooreofe nu. Kọ́ lati da akoko Olorun mo, ati lati mu ise re wa ni ibamu pelu ife Re. Nigba ti a ba nrin ni isise pelu akoko Re, gbogbo ohun a bo si ipo.

Asaro: Akoko Olorun ni o n dari igba eniyan; lo akoko re daradara.

 

BIBELI KIKA: Oniwaasu 3:1-8

ADURA: Oluwa, ko mi lati mo iyi akoko ati lati le lo fun ogo Re, Amin.

 

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *