A FAITHFUL WITNESS
THE SEED
“So I solemnly declare to you this very day: if any of you should be lost, I am not responsible. For I have not held back from announcing to you the whole purpose of God.” — Acts 20:26–27 (GNB)
Paul boldly declared that he had fully delivered God’s message to the people under his watch. His heart was free of guilt because he had told them the truth without fear or compromise. His example shows us what it means to be a faithful messenger of Christ. God has placed people in each of our lives — friends, family, colleagues, neighbours. We carry a responsibility to speak truth in love and to point them to Christ. Silence, compromise, or fear can keep others in darkness. Beloved, we must never hold back from sharing the message that brings life. Let your words, actions, and testimony point others to God’s truth. That is the heart of true evangelism.
Reflection: A faithful witness tells the truth without fear or compromise.
BIBLE READING: Ezekiel 3:17–21
PRAYER: Lord, help me to speak Your truth boldly and in love to everyone You send my way. Amen.
ẸLẸ́RÌÍ OLÓÒÓTỌ́
IRUGBIN NAA
“Nítorí náà mo kéde fún yín ní gbangba lónìí: bí ẹnikẹ́ni nínú yín bá sọnù, èmi kò ní ẹ̀bi. Nítorí èmi kò fà sẹ́yìn láti kéde gbogbo ète Ọlọ́run fún yín”. – Ìṣe Àwọn Aposteli 20:26-27
Pọ́ọ̀lù fi ìgboyà kéde pé òun ti fi ìhìn-iṣẹ́ Ọlọ́run hàn fún àwọn ènìyàn tí ó wà lábẹ́ àkóso rẹ̀. Ọkàn rẹ̀ kò ní ẹ̀bi nítorí pé ó ti sọ òtítọ́ fún wọn láìsí ìbẹ̀rù tàbí ìforígbárí. Àpẹẹrẹ rẹ̀ fi ohun tí ó túmọ̀ sí láti jẹ́ ìránṣẹ́ olóòótọ́ ti Kristi.
Ọlọ́run ti fi àwọn ènìyàn sí ìgbésí ayé wa lokọ̀ọ̀kan , àwọn ọ̀rẹ́, ìdílé, àwọn ẹlẹgbẹ́, àwọn aládùúgbò. A ní iṣẹ́ láti sọ òtítọ́ ní ìfẹ́ àti láti tọ́ka sí Kristi. Ìdákẹ́jẹ́ẹ́, ìforígbárí, tàbí ìbẹ̀rù lè pa àwọn ẹlòmíràn mọ́ sínú òkùnkùn. Olùfẹ́, a kò gbọdọ̀ fà sẹ́yìn láti pín ìhìn-rere tí ó ń mú ìyè wá. Jẹ́ kí ọ̀rọ̀, ìṣe, àti ẹ̀rí rẹ tọ́ àwọn ẹlòmíràn sí òtítọ́ Ọlọ́run. Ìyẹn ni ọkàn ìhìn-rere tòótọ́.
Asaro: Ẹlẹ́rìí olóòótọ́ ń sọ òtítọ́ láìsí ìbẹ̀rù tàbí ìforígbárí.
BIBELI KIKA: Esekieli 3:17-21
ADURA: Olúwa, ràn mí lọ́wọ́ láti sọ òtítọ́ rẹ pẹ̀lú ìgboyà àti ìfẹ́ sí gbogbo ènìyàn tí o rán mi lọ ba. Àmín.