HUMILITY LIKE A CHILD

HUMILITY LIKE A CHILD

THE SEED

“And said, Verily I say unto you, Except ye be converted, and become as little children, ye shall not enter into the kingdom of heaven.” — Matthew 18:3 (KJV)

The disciples of Jesus asked who was greatest in the kingdom, expecting an answer about power or position. But Jesus turned their thinking upside down. He pointed to a little child, teaching that true greatness is rooted in humility, trust, and lowliness of heart. Children are fully dependent on their caregivers; they trust without hesitation. In the same way, believers must depend on God without pride or self-reliance. We must trade worldly ambition for childlike faith.

Beloved, no matter your status, education, or achievements, the kingdom calls for humility. The way up in God’s kingdom is down — a heart bowed in simple, trusting obedience.

Reflection: Greatness in God’s kingdom begins with humility.

 

BIBLE READING: Matthew 18:1–5

PRAYER: Lord, give me a humble, childlike heart that fully depends on You. Amen.

 

ÌRẸ̀LẸ̀ BÍI ỌMỌDÉ

IRUGBIN NAA

“Ó sì wí pé, Lóòtọ́ ni mo wí fún yín, Àyàfi tí ẹ bá yípadà, tí ẹ sì dàbí àwọn ọmọ kékeré, ẹ̀yin kì yóò wọ ìjọba ọ̀run.” – Mátíù 18:3

Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Jésù béèrè ẹni tí ó tóbi jùlọ ní ìjọba Orun wọ́n ń retí ìdáhùn nípa agbára tàbí ipò. Ṣùgbọ́n Jésù yí ìrònú wọn padà. Ó tọ́ka sí ọmọ kékeré kan, ó ń kọ́ni pé ìtóbi tòótọ́ ní ìpìlẹ̀ nínú ìrẹ̀lẹ̀, ìgbẹ́kẹ̀lé, àti ìrẹ̀lẹ̀ ọkàn. Àwọn ọmọdé gbára lé àwọn olùtọ́jú wọn pátápátá; wọ́n gbẹ́kẹ̀lé láìsí ìjákulẹ̀. Bákan náà, àwọn onígbàgbọ́ gbọ́dọ̀ gbẹ́kẹ̀lé Ọlọ́run láìsí ìgbéraga tàbí ìgbẹ́kẹ̀lé ara-ẹni. A gbọ́dọ̀ se pàṣípààrọ̀ ìfẹ́ ayé fún ìgbàgbọ́ bí ọmọdé. Olùfẹ́, láìka ipò rẹ, ẹ̀kọ́ rẹ, tàbí àṣeyọrí rẹ sí, ìjọba náà ń béèrè fún ìrẹ̀lẹ̀. Ọ̀nà àtiga nínú ìjọba Ọlọ́run ni ọkàn tí ó tẹrí ba nínú ìgbọràn tí ó sì gbẹ́kẹ̀lé e.

Asaro: Titóbi nínú ìjọba Ọlọ́run bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ìrẹ̀lẹ̀.

 

BIBELI KIKA: Mátíù 18:1-5

ADURA: Olúwa, fún mi ní ọkàn ìrẹ̀lẹ̀, bí ọmọdé tí ó gbẹ́kẹ̀lé ọ pátápátá. Àmín.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *