TRAINING YOUR THOUGHTS FOR OBEDIENCE

TRAINING YOUR THOUGHTS FOR OBEDIENCE

THE SEED

“We demolish arguments and every pretension that sets itself up against the knowledge of God, and we take captive every thought to make it obedient to Christ.” — 2 Corinthians 10:5 (NIV)

Obedience begins in the mind. Arguments, imaginations, and subtle pride often rise against the knowledge of God long before disobedience shows in behavior. Scripture teaches us to confront these inner resistances and bring them under Christ’s authority. Jesus modeled this in the wilderness: He answered temptation with, “It is written,” refusing to let ungodly suggestions lodge in His heart. We must learn the same rhythm—identify the lies of satan, declare the truth, and act in step with the Spirit. Make a habit of filtering your thoughts through God’s Word. As you consistently say “no” to defiant thoughts, the Spirit strengthens your “yes” to Christ.

Reflection: Captive thoughts lead to obedient steps.

 

BIBLE READING: 2 Corinthians 10:3–6

PRAYER: Lord Jesus, train my mind by Your Word. Help me demolish lies and walk in obedience. Amen.

 

KÍKỌ́ ÀWỌN ÈRÒ RẸ FÚN ÌGBỌRÀN

IRUGBIN NAA

 

“Awa nsọ gbogbo ero kalẹ, ati gbogbo ohun giga ti ngbé ara rẹ̀ ga si ìmọ Ọlọrun, awa si ndi gbogbo ero ni igbekun wá si itẹriba fun Kristi.” – 2 Kọ́ríńtì 10:5

Ìgbọràn bẹ̀rẹ̀ nínú ọkàn. Àríyànjiyàn, èrò inú, àti ìgbéraga lábẹ́lẹ́ sábà máa ń dìde sí ìmọ̀ Ọlọ́run kí àìgbọ́ràn tó farahàn nínú ìwà. Ìwé Mímọ́ kọ́ wa láti kojú àwọn àtakò inú wọ̀nyí kí a sì mú wọn wá sábẹ́ àṣẹ Kristi. Jésù fi èyí hàn ní aginjù: Ó dáhùn ìdánwò pẹ̀lú “A ti kọ ọ́”, tí ko si gba àwọn àbá búburú laaye ninú ọkàn Rẹ̀. Awa naa gbodo rin ni ilana yii – ki a mo itanje satani, ki a kéde òtítọ́, kí a sì hùwà ní si sise pẹ̀lú Ẹ̀mí. Jẹ́ kí ó je ise re láti ṣàtúnṣe èrò rẹ nipase Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run. Bí o ṣe ń sọ “bẹ́ẹ̀kọ́” sí àwọn èrò buburu nígbà gbogbo, Ẹ̀mí ń fún “bẹ́ẹ̀ni” rẹ lágbára sí ninu Kristi.

Asaro: Àwọn èrò ìgbèkùn máa ń yọrí sí àwọn ìgbésẹ̀ ìgbọràn.

 

BIBELI KIKA: 2 Kọ́ríńtì 10:3-6

ADURA: Olúwa Jésù, kọ́ èrò inú mi nípa Ọ̀rọ̀ Rẹ. Ràn mí lọ́wọ́ láti pa irọ́ run kí n sì máa rìn ní ìgbọràn. Àmín.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *