PREVAILING PRAYER THE SEED 

 

MAY  

1 SUN 2022 

“And being in an agony he prayed more earnestly: and his sweat was as it were great  drops of blood falling down to the ground.” Luke 22:44 

Prevailing, or effectual prayer, is that prayer which effectually moves God. The mystery  of victory is revealed in the place of prayer. Jesus could not have completed his ministry without  prevailing prayers. It was prayer against the serious contention that were unleashed against  Him. Anything that overwhelms you spiritually has defeated you physically. If you want to win  and walk in the realm of ceaseless victories in any battle at all, your prayer must be intense; you  must have a garden of prayer. 

Dearly beloved, you must sweat it out in the garden of prayer to walk in sweatless  victories this year. Before any major project or assignment, settle it in the place of prayer. Your personal prayer altar is the most important thing in your life. That is the place that  is called ‘there’; the place where you will meet with God. That is where all issues are settled  including the mystery over stubborn challenges. Jesus encountered a stubborn challenge,  drenched in sweat while praying, after which he was able to face the cross. PRAYER 

Father Lord, grant me the power of prevailing prayer everyday of my life In Jesus Name Amen. BIBLE READINGS: Psalms 17 

ADURA AGBAYORI 

IRUGBIN NAA 

“Bi o si ti wa ni iwaya-ija, o n gbadura si i kikankikan: ogun re si dabi iro eje nla, o n kan  sile.” Luku 22:44 

Adura agbayori tabi adura olododo je adura ti o maa n se itewogba lodo Olorun. A maa  n fi ijinle isegun han ni ibi adura. 

Jesu ki ba ma ti pari ise ti Olorun ran laisi adura agbayori. Eyi ni adura ti o fi bori awon inunibini  ti won se si i. 

Ohunkohun ti o ba lagbara ju o lo ninu emi, o ti segun re ninu ara. Bi o ba fe bori, ki o si  rin kuro ninu ogun ni isegun ti ko ni opin, adura re gbodo gbona, o si gbodo ni ogba adura. Olufe owon, o ni lati laagun ni ogba adura ki o baa le rin ninu isegun ti ko si aagun lodun yii. Ki o  to dawo le ohun Pataki kan tabi ise, koko yanju re ni ibi adura. 

Pepe adura ti o je ti iwo funra re se Pataki ninu aye re. ibi yi ni a n pe ni ibe, ibi ti iwo yio ti ba  Olorun pade. 

Nibe ni a ti n yanju gbogbo isoro ati ijinle lori ipenija ti o lagbara. 

Jesu koju ipenija ti o lagbara, oogun si boo nigba ti o n gba adura, leyin eyi ti o ni agbara lati  dojuko agbelebu. 

ADURA 

Baba Oluwa, fun mi ni agbara adura agbayori ni ojoojumo aye mi ni Oruko Jesu. Amin BIBELI KIKA: Orin Dafidi 17 

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *