HE PROTECTS AND CARES FOR US
THE SEED
MAY 16 MON 2022
“Get up,” he said, “take the child and his mother and escape to Egypt. Stay there until I tell you, for Herod is going to search for the child to kill him.” Matthew 2: 13 When my younger brother was born, a local woman requested to visit the baby, but God had divinely warned our parents to take the baby away from home. This woman was led to the house, but she refused to come into the house, saying that the baby had been taken away from the house.
In Matthew 2: 1-15, the wise men went to visit Jesus, but they were divinely warned not to return to Herod.
Joseph was also divinely instructed through a dream to flee to Egypt with the baby and mother.
The power of God is unlimited when you walk with the Lord and enemies lurk around to attack you. He will not leave you vulnerable to the attack but protect you from it by sending His warnings. However, being victorious depends on your adhering to His warnings and by acting accordingly.
PRAYER
Lord, continue to protect and care for me through your divine guidance
BIBLE READINGS: Matthew 6:25-34, Philippians 4:6-7
ABO ATI IKE RE WA FUN WA
IRUGBIN NAA
Dide, gbe omo owo naa pelu iya re, ki o si salo si egipti, ki iwo kio si gbe ibe titi emi o fi so fun o. Nitori Herodu yio wa omo naa lati pa. Matthew 2:13
Nigba ti won bi aburo mi, obirin kan fe lati ri omo naa, sugbon Olorun ti so fun awon obi mi wipe ki won gbe omo naa kuro ni ile. Won mu obirin naa wa si ile sugbon o ko lati wole, o so wipe won tig be omo naa kuro ni ile.
Ninu Matthew 2: 1-15, awon amoye lo lati wo Jesu, sugbon won ri ikiol wipe ki won mase pada si odo Herodu.
Josefu naa ri ikilo nipa ala wipe ki o sa kuro ni egipti pelu iya ati omo. Agbara Olorun ko ni ipekun. Nigba ti o ba Olorun rin, ti ota si ndode re, ko ni fi o sile fun ota sugbon yio ran ikilo si o.
Isegun wa daju nigba ti a ba gboran si ikilo naa, nipa titele ikilo naa.
ADURA
Oluwa, tesiwaju lati maa daaboo mi, ati lati maa toju mi, nipase itosona atorun Re. BIBELI KIKA: Matthew 6:25-34, Philippians 4:6-7